Surah Ash-Sharh ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah Ash-Sharh pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (8 Ẹsẹ — مكية). Ash-Sharh Gbọ, Ash-Sharh Itumọ, Ash-Sharh mp3, Ash-Sharh pdf.

Ka ati Gbọ Surah Ash-Sharh

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy
M Mahmoud Khalil Al-Husary
A Abdurrahman As-Sudais
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi
A Abdul Basit Abdul Samad
A Ali Al-Hudhaify
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy
A Abu Bakr Ash-Shaatree
M Muhammad Ayyoub
A Abdullah Basfar
A Abdullah Al-Juhani
M Maher Al Muaiqly
x1
أَلَمْ نَشْرَحْ لَكَ صَدْرَكَ ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
Se A o sipaya igba-aya re fun o bi
وَوَضَعْنَا عَنكَ وِزْرَكَ ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
A si gbe ese re kuro lorun re
الَّذِي أَنقَضَ ظَهْرَكَ ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
eyi ti o wo o lorun. amo ti onitoun pada gba ’Islam ibaa je pe o gba a ni owuro
وَرَفَعْنَا لَكَ ذِكْرَكَ ۝٤
📖 Itumọ Ẹsẹ 4
A si gbe iranti oruko re ga fun o
فَإِنَّ مَعَ الْعُسْرِ يُسْرًا ۝٥
📖 Itumọ Ẹsẹ 5
Nitori naa, dajudaju idekun wa leyin inira
إِنَّ مَعَ الْعُسْرِ يُسْرًا ۝٦
📖 Itumọ Ẹsẹ 6
Dajudaju idekun wa leyin inira se
فَإِذَا فَرَغْتَ فَانصَبْ ۝٧
📖 Itumọ Ẹsẹ 7
Nitori naa, nigba ti o ba buse (lori okan), gbiyanju (omiran)
وَإِلَىٰ رَبِّكَ فَارْغَب ۝٨
📖 Itumọ Ẹsẹ 8
Odo Oluwa re si ni ki o soju kokoro oore si
← 93 Ash-Sharh (94/114) 95 →
Kika Surah Ash-Sharh ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

94الشرح Ash-Sharh 📚 8 Ẹsẹ مكية

Ẹsẹ kọọkan – Surah Ash-Sharh — 8 Ẹsẹ




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers