An-Nahl · 90/128
Itumọ Aṣẹ ohun — An-Nahl
۞ إِنَّ اللَّهَ يَأْمُرُ بِالْعَدْلِ وَالْإِحْسَانِ وَإِيتَاءِ ذِي الْقُرْبَىٰ وَيَنْهَىٰ عَنِ الْفَحْشَاءِ وَالْمُنكَرِ وَالْبَغْيِ ۚ يَعِظُكُمْ لَعَلَّكُمْ تَذَكَّرُونَ ۝٩٠
Innal laaha yaamaru bil `adli wal ihsaani wa eetaaa`i zil qurbaa wa yanhaa `anil fahshaaa`i wal munkari walbagh-i` ya`izukum la`allakum tazakkkaroon
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju Allahu n pase sise deede, sise rere ati fifun ebi (ni nnkan). O si n ko iwa ibaje, ohun buruku ati rukerudo. O n se waasi fun yin nitori ki e le lo iranti

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 88-92 — An-Nahl

88الَّذِينَ كَفَرُوا وَصَدُّوا عَن سَبِيلِ اللَّهِ زِدْنَاهُمْ عَذَابًا فَوْقَ الْعَذَابِ بِمَا كَانُوا يُفْسِدُونَ
Awon t’o sai gbagbo, ti won si seri awon eniyan kuro loju ona (esin) Allahu, A o se alekun iya lori iya fun won nitori pe won n sebaje
89وَيَوْمَ نَبْعَثُ فِي كُلِّ أُمَّةٍ شَهِيدًا عَلَيْهِم مِّنْ أَنفُسِهِمْ ۖ وَجِئْنَا بِكَ شَهِيدًا عَلَىٰ هَٰؤُلَاءِ ۚ وَنَزَّلْنَا عَلَيْكَ الْكِتَابَ تِبْيَانًا لِّكُلِّ شَيْءٍ وَهُدًى وَرَحْمَةً وَبُشْرَىٰ لِلْمُسْلِمِينَ
(Ranti) Ojo ti A oo gbe elerii dide fun ijo kookan laaarin ara won, A si maa mu iwo wa ni elerii fun awon wonyi. A so Tira kale fun o; (o je) alaye fun gbogbo nnkan, imona, ike ati iro idunnu fun awon musulumi
90۞ إِنَّ اللَّهَ يَأْمُرُ بِالْعَدْلِ وَالْإِحْسَانِ وَإِيتَاءِ ذِي الْقُرْبَىٰ وَيَنْهَىٰ عَنِ الْفَحْشَاءِ وَالْمُنكَرِ وَالْبَغْيِ ۚ يَعِظُكُمْ لَعَلَّكُمْ تَذَكَّرُونَ
Dajudaju Allahu n pase sise deede, sise rere ati fifun ebi (ni nnkan). O si n ko iwa ibaje, ohun buruku ati rukerudo. O n se waasi fun yin nitori ki e le lo iranti
91وَأَوْفُوا بِعَهْدِ اللَّهِ إِذَا عَاهَدتُّمْ وَلَا تَنقُضُوا الْأَيْمَانَ بَعْدَ تَوْكِيدِهَا وَقَدْ جَعَلْتُمُ اللَّهَ عَلَيْكُمْ كَفِيلًا ۚ إِنَّ اللَّهَ يَعْلَمُ مَا تَفْعَلُونَ
Ki e si mu adehun Allahu se nigba ti e ba se adehun. E ma se tu ibura leyin ifirinle re. E si kuku ti fi Allahu se Elerii lori ara yin. Dajudaju Allahu mo ohun ti e n se nise
92وَلَا تَكُونُوا كَالَّتِي نَقَضَتْ غَزْلَهَا مِن بَعْدِ قُوَّةٍ أَنكَاثًا تَتَّخِذُونَ أَيْمَانَكُمْ دَخَلًا بَيْنَكُمْ أَن تَكُونَ أُمَّةٌ هِيَ أَرْبَىٰ مِنْ أُمَّةٍ ۚ إِنَّمَا يَبْلُوكُمُ اللَّهُ بِهِ ۚ وَلَيُبَيِّنَنَّ لَكُمْ يَوْمَ الْقِيَامَةِ مَا كُنتُمْ فِيهِ تَخْتَلِفُونَ
Ki e si ma se da bi (obinrin) eyi ti o tu owu didi re pale leyin ti o ti di i le. Nse ni e n lo ibura yin fun etan laaarin ara yin nitori pe iran kan po ju iran kan lo. Dajudaju Allahu n dan yin wo pelu re ni. Ati pe ni Ojo Ajinde O kuku maa salaye fun yin ohun ti e n yapa enu si
An-NahlAtokọ Kurani
128Ẹsẹ
MeccanRevelation
90Ẹsẹ

Itumọ — An-Nahl 90

Surah An-Nahl Ẹsẹ 90 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju Allahu n pase sise deede, sise rere ati fifun…

Surah Ẹsẹ 90/128 — An-Nahl النحل (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: An-Nahl Gbọ, An-Nahl Itumọ, An-Nahl mp3, An-Nahl pdf. Ẹsẹ 88–92. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers