Al-Baqarah · 203/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Baqarah
۞ وَاذْكُرُوا اللَّهَ فِي أَيَّامٍ مَّعْدُودَاتٍ ۚ فَمَن تَعَجَّلَ فِي يَوْمَيْنِ فَلَا إِثْمَ عَلَيْهِ وَمَن تَأَخَّرَ فَلَا إِثْمَ عَلَيْهِ ۚ لِمَنِ اتَّقَىٰ ۗ وَاتَّقُوا اللَّهَ وَاعْلَمُوا أَنَّكُمْ إِلَيْهِ تُحْشَرُونَ ۝٢٠٣
Wazkurul laaha feee ayyaamim ma`doodaat; faman ta`ajjala fee yawmaini falaaa ismaa `alaihi wa man taakhkhara falaaa isma `alayh; limanit-taqaa; wattaqul laaha wa`lamooo annakum ilaihi tuhsharoon
📖 Ni Yorùbá
E seranti Allahu laaarin awon ojo t’o ni onka. Nitori naa, eni ti o ba kanju (se e) fun ojo meji, ko si ese fun un. Eni ti o ba keyin (ti o duro di ojo keta), ko si ese fun un fun eni ti o ba sora (fun iwa ese). E beru Allahu. Ki e si mo pe dajudaju won yoo ko yin jo si odo Re
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 201-205 — Al-Baqarah

201وَمِنْهُم مَّن يَقُولُ رَبَّنَا آتِنَا فِي الدُّنْيَا حَسَنَةً وَفِي الْآخِرَةِ حَسَنَةً وَقِنَا عَذَابَ النَّارِ
O si n be ninu won, eni t’o n so pe: "Oluwa wa, fun wa ni oore ni aye ati oore ni orun, ki O si so wa nibi iya Ina
202أُولَٰئِكَ لَهُمْ نَصِيبٌ مِّمَّا كَسَبُوا ۚ وَاللَّهُ سَرِيعُ الْحِسَابِ
Awon wonyen, tiwon ni ipin oore nipa ohun ti won se nise. Allahu si ni Oluyara nibi isiro-ise
203۞ وَاذْكُرُوا اللَّهَ فِي أَيَّامٍ مَّعْدُودَاتٍ ۚ فَمَن تَعَجَّلَ فِي يَوْمَيْنِ فَلَا إِثْمَ عَلَيْهِ وَمَن تَأَخَّرَ فَلَا إِثْمَ عَلَيْهِ ۚ لِمَنِ اتَّقَىٰ ۗ وَاتَّقُوا اللَّهَ وَاعْلَمُوا أَنَّكُمْ إِلَيْهِ تُحْشَرُونَ
E seranti Allahu laaarin awon ojo t’o ni onka. Nitori naa, eni ti o ba kanju (se e) fun ojo meji, ko si ese fun un. Eni ti o ba keyin (ti o duro di ojo keta), ko si ese fun un fun eni ti o ba sora (fun iwa ese). E beru Allahu. Ki e si mo pe dajudaju won yoo ko yin jo si odo Re
204وَمِنَ النَّاسِ مَن يُعْجِبُكَ قَوْلُهُ فِي الْحَيَاةِ الدُّنْيَا وَيُشْهِدُ اللَّهَ عَلَىٰ مَا فِي قَلْبِهِ وَهُوَ أَلَدُّ الْخِصَامِ
O n be ninu awon eniyan, eni ti oro (enu) re yo maa se o ni kayefi ninu isemi aye yii, ti yo si maa fi Allahu jerii si ohun ti n be ninu okan re (pe ko si ija), onija t’o le julo si ni
205وَإِذَا تَوَلَّىٰ سَعَىٰ فِي الْأَرْضِ لِيُفْسِدَ فِيهَا وَيُهْلِكَ الْحَرْثَ وَالنَّسْلَ ۗ وَاللَّهُ لَا يُحِبُّ الْفَسَادَ
Nigba ti o ba si yise pada, o maa sise kiri lori ile nitori ki o le sebaje sori ile, ki o si le pa nnkan oko ati eran-osin run. Allahu ko si feran ibaje
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
203Ẹsẹ

Itumọ — Al-Baqarah 203

Surah Al-Baqarah Ẹsẹ 203 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : E seranti Allahu laaarin awon ojo t’o ni onka. Nitori…

Surah Ẹsẹ 203/286 — Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Baqarah Gbọ, Al-Baqarah Itumọ, Al-Baqarah mp3, Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 201–205. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers