At-Talaq · 9/12
Itumọ Aṣẹ ohun — At-Talaq
فَذَاقَتْ وَبَالَ أَمْرِهَا وَكَانَ عَاقِبَةُ أَمْرِهَا خُسْرًا ٩
Transliteration
Fazaaqat wabbala amrihaa wa kaana `aaqibatu amrihaa khusraa
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Nitori naa, won to iya oran won wo. Ikangun oro won si je ofo
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 7-11 — At-Talaq
7لِيُنفِقْ ذُو سَعَةٍ مِّن سَعَتِهِ ۖ وَمَن قُدِرَ عَلَيْهِ رِزْقُهُ فَلْيُنفِقْ مِمَّا آتَاهُ اللَّهُ ۚ لَا يُكَلِّفُ اللَّهُ نَفْسًا إِلَّا مَا آتَاهَا ۚ سَيَجْعَلُ اللَّهُ بَعْدَ عُسْرٍ يُسْرًا
Ki oloro na ninu oro re. Eni ti A si diwon arisiki re fun (niwonba), ki o na ninu ohun ti Allahu fun un. Allahu ko labo emi kan lorun ayafi nnkan ti O fun un. Allahu yo si mu irorun wa leyin inira
8وَكَأَيِّن مِّن قَرْيَةٍ عَتَتْ عَنْ أَمْرِ رَبِّهَا وَرُسُلِهِ فَحَاسَبْنَاهَا حِسَابًا شَدِيدًا وَعَذَّبْنَاهَا عَذَابًا نُّكْرًا
Meloo meloo ninu awon ilu ti won yapa ase Oluwa Re ati awon Ojise Re. A si maa siro ise won ni isiro lile. Ati pe A maa je won niya t’o buru gan-an
9فَذَاقَتْ وَبَالَ أَمْرِهَا وَكَانَ عَاقِبَةُ أَمْرِهَا خُسْرًا
Nitori naa, won to iya oran won wo. Ikangun oro won si je ofo
10أَعَدَّ اللَّهُ لَهُمْ عَذَابًا شَدِيدًا ۖ فَاتَّقُوا اللَّهَ يَا أُولِي الْأَلْبَابِ الَّذِينَ آمَنُوا ۚ قَدْ أَنزَلَ اللَّهُ إِلَيْكُمْ ذِكْرًا
Allahu ti pese iya lile sile de won. Nitori naa, e beru Allahu, eyin onilaakaye ti e gbagbo ni ododo. Allahu kuku ti so iranti kale fun yin
11رَّسُولًا يَتْلُو عَلَيْكُمْ آيَاتِ اللَّهِ مُبَيِّنَاتٍ لِّيُخْرِجَ الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ مِنَ الظُّلُمَاتِ إِلَى النُّورِ ۚ وَمَن يُؤْمِن بِاللَّهِ وَيَعْمَلْ صَالِحًا يُدْخِلْهُ جَنَّاتٍ تَجْرِي مِن تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ خَالِدِينَ فِيهَا أَبَدًا ۖ قَدْ أَحْسَنَ اللَّهُ لَهُ رِزْقًا
Ojise kan ti o maa ke awon ayah Allahu t’o yanju fun yin nitori ki o le mu awon t’o gbagbo ni ododo, ti won tun se awon ise rere, kuro ninu awon okunkun lo sinu imole. Enikeni ti o ba gba Allahu gbo ni ododo, ti o si n se ise rere, O maa mu un wo inu awon Ogba Idera, ti awon odo n san ni isale re. Olusegbere ni won ninu re titi laelae. Dajudaju Allahu ti se arisiki t’o dara julo fun un
At-TalaqAtokọ Kurani
12Ẹsẹ
MedinanRevelation
9Ẹsẹ
Itumọ — At-Talaq 9
Surah At-Talaq Ẹsẹ 9 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Nitori naa, won to iya oran won wo. Ikangun oro…Surah Ẹsẹ 9/12 — At-Talaq الطلاق (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: At-Talaq Gbọ, At-Talaq Itumọ, At-Talaq mp3, At-Talaq pdf. Ẹsẹ 7–11. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








