Al-Qalam · 9/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Qalam
وَدُّوا لَوْ تُدْهِنُ فَيُدْهِنُونَ ۝٩
Waddoo law tudhinu fa-yudhinoon
📖 Ni Yorùbá
Ati pe won fe ki o dewo, ki awon naa si dewo
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 7-11 — Al-Qalam

7إِنَّ رَبَّكَ هُوَ أَعْلَمُ بِمَن ضَلَّ عَن سَبِيلِهِ وَهُوَ أَعْلَمُ بِالْمُهْتَدِينَ
Dajudaju Oluwa re, O nimo julo nipa eni t’o sina kuro loju ona Re. O si nimo julo nipa awon olumona
8فَلَا تُطِعِ الْمُكَذِّبِينَ
Nitori naa, ma se tele awon olupe-ododo-niro
9وَدُّوا لَوْ تُدْهِنُ فَيُدْهِنُونَ
Ati pe won fe ki o dewo, ki awon naa si dewo
10وَلَا تُطِعْ كُلَّ حَلَّافٍ مَّهِينٍ
Ma se tele gbogbo eni ti ibura re po, eni yepere
11هَمَّازٍ مَّشَّاءٍ بِنَمِيمٍ
abuni, alarinka t’o n sofofo kiri
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
9Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 9

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 9 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ati pe won fe ki o dewo, ki awon naa…

Surah Ẹsẹ 9/52 — Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Qalam Gbọ, Al-Qalam Itumọ, Al-Qalam mp3, Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 7–11. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers