Al-Qalam · 8/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
فَلَا تُطِعِ الْمُكَذِّبِينَ ۝٨
Falaa tuti`il mukazzibeen
📖 Ni Yorùbá
Nitori naa, ma se tele awon olupe-ododo-niro

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 6-10 — Surah Al-Qalam

6بِأَييِّكُمُ الْمَفْتُونُ
ewo ninu yin ni were
7إِنَّ رَبَّكَ هُوَ أَعْلَمُ بِمَن ضَلَّ عَن سَبِيلِهِ وَهُوَ أَعْلَمُ بِالْمُهْتَدِينَ
Dajudaju Oluwa re, O nimo julo nipa eni t’o sina kuro loju ona Re. O si nimo julo nipa awon olumona
8فَلَا تُطِعِ الْمُكَذِّبِينَ
Nitori naa, ma se tele awon olupe-ododo-niro
9وَدُّوا لَوْ تُدْهِنُ فَيُدْهِنُونَ
Ati pe won fe ki o dewo, ki awon naa si dewo
10وَلَا تُطِعْ كُلَّ حَلَّافٍ مَّهِينٍ
Ma se tele gbogbo eni ti ibura re po, eni yepere
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
8Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 8

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 8 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Nitori naa, ma se tele awon olupe-ododo-niro

Surah Ẹsẹ 8/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 6–10. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers