Ash-Shu'ara · 194/227
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Ash-Shu'ara
عَلَىٰ قَلْبِكَ لِتَكُونَ مِنَ الْمُنذِرِينَ ۝١٩٤
Alaa qalbika litakoona minal munzireen
📖 Ni Yorùbá
sinu okan re nitori ki o le wa ninu awon olukilo

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 192-196 — Surah Ash-Shu'ara

192وَإِنَّهُ لَتَنزِيلُ رَبِّ الْعَالَمِينَ
Dajudaju al-Ƙur’an, won so o kale ni lati odo Oluwa gbogbo eda
193نَزَلَ بِهِ الرُّوحُ الْأَمِينُ
Molaika Jibril, olufokantan l’o so o kale
194عَلَىٰ قَلْبِكَ لِتَكُونَ مِنَ الْمُنذِرِينَ
sinu okan re nitori ki o le wa ninu awon olukilo
195بِلِسَانٍ عَرَبِيٍّ مُّبِينٍ
pelu ede Larubawa ponnbele
196وَإِنَّهُ لَفِي زُبُرِ الْأَوَّلِينَ
Dajudaju (oro nipa re) ti wa ninu ipin-ipin Tira awon eni akoko
Ash-Shu'araAtokọ Kurani
227Ẹsẹ
MeccanRevelation
194Ẹsẹ

Itumọ — Ash-Shu'ara 194

Surah Ash-Shu'ara Ẹsẹ 194 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : sinu okan re nitori ki o le wa ninu awon…

Surah Ẹsẹ 194/227 — Surah Ash-Shu'ara الشعراء (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Ash-Shu'ara Gbọ, Surah Ash-Shu'ara Itumọ, Surah Ash-Shu'ara mp3, Surah Ash-Shu'ara pdf. Ẹsẹ 192–196. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers