Aal-Imran · 149/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Aal-Imran
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا إِن تُطِيعُوا الَّذِينَ كَفَرُوا يَرُدُّوكُمْ عَلَىٰ أَعْقَابِكُمْ فَتَنقَلِبُوا خَاسِرِينَ ۝١٤٩
Yaaa `aiyuhal lazeena aamanoo in tutee`ullazeena kafaroo yaruddookum `alaaa a`qaabkum fatanqaliboo khaasireen
📖 Ni Yorùbá
Eyin ti e gbagbo ni ododo, ti e ba tele awon t’o sai gbagbo, won maa yi yin lese pada kuro ninu esin. Nigba naa, e maa pada di eni ofo (sinu aigbagbo)
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 147-151 — Aal-Imran

147وَمَا كَانَ قَوْلَهُمْ إِلَّا أَن قَالُوا رَبَّنَا اغْفِرْ لَنَا ذُنُوبَنَا وَإِسْرَافَنَا فِي أَمْرِنَا وَثَبِّتْ أَقْدَامَنَا وَانصُرْنَا عَلَى الْقَوْمِ الْكَافِرِينَ
Ko si si ohun kan ti won so tayo pe won so pe: "Oluwa wa fori awon ese wa ati aseju wa ninu oro wa jin wa, mu ese wa duro sinsin, ki O si se aranse fun wa lori ijo alaigbagbo
148فَآتَاهُمُ اللَّهُ ثَوَابَ الدُّنْيَا وَحُسْنَ ثَوَابِ الْآخِرَةِ ۗ وَاللَّهُ يُحِبُّ الْمُحْسِنِينَ
Nitori naa, Allahu fun won ni esan aye ati daadaa esan orun. Allahu si nifee awon oluse rere
149يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا إِن تُطِيعُوا الَّذِينَ كَفَرُوا يَرُدُّوكُمْ عَلَىٰ أَعْقَابِكُمْ فَتَنقَلِبُوا خَاسِرِينَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, ti e ba tele awon t’o sai gbagbo, won maa yi yin lese pada kuro ninu esin. Nigba naa, e maa pada di eni ofo (sinu aigbagbo)
150بَلِ اللَّهُ مَوْلَاكُمْ ۖ وَهُوَ خَيْرُ النَّاصِرِينَ
Allahu si ni Alaranse yin. O si loore julo ninu awon alaranse
151سَنُلْقِي فِي قُلُوبِ الَّذِينَ كَفَرُوا الرُّعْبَ بِمَا أَشْرَكُوا بِاللَّهِ مَا لَمْ يُنَزِّلْ بِهِ سُلْطَانًا ۖ وَمَأْوَاهُمُ النَّارُ ۚ وَبِئْسَ مَثْوَى الظَّالِمِينَ
A maa fi eru jeje sinu okan awon t’o sai gbagbo nitori pe won ba Allahu wa akegbe, eyi ti ko so eri kan kale fun. Ina si ni ibugbe won; ile awon alabosi si buru
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
149Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 149

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 149 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Eyin ti e gbagbo ni ododo, ti e ba tele…

Surah Ẹsẹ 149/200 — Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Aal-Imran Gbọ, Aal-Imran Itumọ, Aal-Imran mp3, Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 147–151. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers