Muhammad · 32/38
Itumọ Aṣẹ ohun — Muhammad
إِنَّ الَّذِينَ كَفَرُوا وَصَدُّوا عَن سَبِيلِ اللَّهِ وَشَاقُّوا الرَّسُولَ مِن بَعْدِ مَا تَبَيَّنَ لَهُمُ الْهُدَىٰ لَن يَضُرُّوا اللَّهَ شَيْئًا وَسَيُحْبِطُ أَعْمَالَهُمْ ۝٣٢
Innnal lazeena kafaroo wa saddoo `an sabeelil laahi wa shaaaqqur Rasoola mim ba`di maa tabaiyana lahumul hudaa lany yadurrul laaha shai`anw wa sa yuhbitu a`maalahum
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju awon t’o sai gbagbo, ti won si seri awon eniyan kuro loju ona (esin) Allahu, ti won tun ko inira ba Ojise Allahu leyin ti imona ti foju han si won, won ko le ko inira kini kan ba Allahu. (Allahu) yo si ba ise won je
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 30-34 — Muhammad

30وَلَوْ نَشَاءُ لَأَرَيْنَاكَهُمْ فَلَعَرَفْتَهُم بِسِيمَاهُمْ ۚ وَلَتَعْرِفَنَّهُمْ فِي لَحْنِ الْقَوْلِ ۚ وَاللَّهُ يَعْلَمُ أَعْمَالَكُمْ
Ati pe ti A ba fe Awa iba fi won han o, iwo iba si mo won pelu ami won. Dajudaju iwo yoo mo won nipa ipekoro-soro (won). Allahu si mo awon ise (owo) yin
31وَلَنَبْلُوَنَّكُمْ حَتَّىٰ نَعْلَمَ الْمُجَاهِدِينَ مِنكُمْ وَالصَّابِرِينَ وَنَبْلُوَ أَخْبَارَكُمْ
Dajudaju A maa dan yin wo titi A fi maa safi han awon olujagun-esin ati awon onisuuru ninu yin. A si maa gbidanwo awon iro yin
32إِنَّ الَّذِينَ كَفَرُوا وَصَدُّوا عَن سَبِيلِ اللَّهِ وَشَاقُّوا الرَّسُولَ مِن بَعْدِ مَا تَبَيَّنَ لَهُمُ الْهُدَىٰ لَن يَضُرُّوا اللَّهَ شَيْئًا وَسَيُحْبِطُ أَعْمَالَهُمْ
Dajudaju awon t’o sai gbagbo, ti won si seri awon eniyan kuro loju ona (esin) Allahu, ti won tun ko inira ba Ojise Allahu leyin ti imona ti foju han si won, won ko le ko inira kini kan ba Allahu. (Allahu) yo si ba ise won je
33۞ يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا أَطِيعُوا اللَّهَ وَأَطِيعُوا الرَّسُولَ وَلَا تُبْطِلُوا أَعْمَالَكُمْ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e tele (oro) Allahu, e tele (oro) Ojise naa, ki e si ma se ba awon ise yin je
34إِنَّ الَّذِينَ كَفَرُوا وَصَدُّوا عَن سَبِيلِ اللَّهِ ثُمَّ مَاتُوا وَهُمْ كُفَّارٌ فَلَن يَغْفِرَ اللَّهُ لَهُمْ
Dajudaju awon t’o sai gbagbo, ti won si seri awon eniyan kuro loju ona (esin) Allahu, leyin naa ti won ku nigba ti won je alaigbagbo, Allahu ko nii forijin won
MuhammadAtokọ Kurani
38Ẹsẹ
MedinanRevelation
32Ẹsẹ

Itumọ — Muhammad 32

Surah Muhammad Ẹsẹ 32 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju awon t’o sai gbagbo, ti won si seri awon…

Surah Ẹsẹ 32/38 — Muhammad محمد (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Muhammad Gbọ, Muhammad Itumọ, Muhammad mp3, Muhammad pdf. Ẹsẹ 30–34. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers