Al-Fath · 4/29
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Fath
هُوَ الَّذِي أَنزَلَ السَّكِينَةَ فِي قُلُوبِ الْمُؤْمِنِينَ لِيَزْدَادُوا إِيمَانًا مَّعَ إِيمَانِهِمْ ۗ وَلِلَّهِ جُنُودُ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ ۚ وَكَانَ اللَّهُ عَلِيمًا حَكِيمًا ۝٤
Huwal lazeee anzalas sakeenata fee quloobil mu`mineena liyazdaadooo eemaanamma`a eemaanihim; wa lillaahi junoodus samawaati wal ard; wa kaanal laahu `Aleeman Hakeemaa
📖 Ni Yorùbá
Oun ni Eni ti O so ifayabale sinu okan awon onigbagbo ododo nitori ki won le lekun ni igbagbo si igbagbo won. Ti Allahu si ni awon omo ogun sanmo ati ile. Allahu si n je Onimo, Ologbon

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 2-6 — Al-Fath

2لِّيَغْفِرَ لَكَ اللَّهُ مَا تَقَدَّمَ مِن ذَنبِكَ وَمَا تَأَخَّرَ وَيُتِمَّ نِعْمَتَهُ عَلَيْكَ وَيَهْدِيَكَ صِرَاطًا مُّسْتَقِيمًا
nitori ki Allahu le saforijin ohun ti o siwaju ninu asise re ati ohun ti o keyin (ninu re), ati nitori ki O le sasepe idera Re le o lori ati nitori ki O le fi ese re rinle soju ona taara (’Islam)
3وَيَنصُرَكَ اللَّهُ نَصْرًا عَزِيزًا
ati nitori ki Allahu le saranse fun o ni aranse t’o lagbara
4هُوَ الَّذِي أَنزَلَ السَّكِينَةَ فِي قُلُوبِ الْمُؤْمِنِينَ لِيَزْدَادُوا إِيمَانًا مَّعَ إِيمَانِهِمْ ۗ وَلِلَّهِ جُنُودُ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ ۚ وَكَانَ اللَّهُ عَلِيمًا حَكِيمًا
Oun ni Eni ti O so ifayabale sinu okan awon onigbagbo ododo nitori ki won le lekun ni igbagbo si igbagbo won. Ti Allahu si ni awon omo ogun sanmo ati ile. Allahu si n je Onimo, Ologbon
5لِّيُدْخِلَ الْمُؤْمِنِينَ وَالْمُؤْمِنَاتِ جَنَّاتٍ تَجْرِي مِن تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ خَالِدِينَ فِيهَا وَيُكَفِّرَ عَنْهُمْ سَيِّئَاتِهِمْ ۚ وَكَانَ ذَٰلِكَ عِندَ اللَّهِ فَوْزًا عَظِيمًا
(O se bee fun won) nitori ki O le mu awon onigbagbo ododo lokunrin ati onigbagbo ododo lobinrin wo inu awon Ogba Idera, eyi ti awon odo n san ni isale re, olusegbere ni won ninu re, ati nitori ki O le pa awon asise won re. Iyen si je erenje nla ni odo Allahu
6وَيُعَذِّبَ الْمُنَافِقِينَ وَالْمُنَافِقَاتِ وَالْمُشْرِكِينَ وَالْمُشْرِكَاتِ الظَّانِّينَ بِاللَّهِ ظَنَّ السَّوْءِ ۚ عَلَيْهِمْ دَائِرَةُ السَّوْءِ ۖ وَغَضِبَ اللَّهُ عَلَيْهِمْ وَلَعَنَهُمْ وَأَعَدَّ لَهُمْ جَهَنَّمَ ۖ وَسَاءَتْ مَصِيرًا
Ati nitori ki O le fiya je awon sobe-selu musulumi lokunrin ati awon sobe-selu musulumi lobinrin, pelu awon osebo lokunrin ati awon osebo lobinrin, awon elerokero nipa Allahu ni ti ero aburu. Apadasi aburu n be fun won. Allahu ti binu si won. O ti sebi le won. O si ti pese ina Jahnamo sile de won. O si buru ni ikangun
Al-FathAtokọ Kurani
29Ẹsẹ
MedinanRevelation
4Ẹsẹ

Itumọ — Al-Fath 4

Surah Al-Fath Ẹsẹ 4 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Oun ni Eni ti O so ifayabale sinu okan awon…

Surah Ẹsẹ 4/29 — Al-Fath الفتح (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Fath Gbọ, Al-Fath Itumọ, Al-Fath mp3, Al-Fath pdf. Ẹsẹ 2–6. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Wednesday, August 19, 2026

Don't forget us in your sincere prayers