Al-Fath · 3/29
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Fath
وَيَنصُرَكَ اللَّهُ نَصْرًا عَزِيزًا ٣
Transliteration
Wa yansurakal laahu nasran `azeezaa
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
ati nitori ki Allahu le saranse fun o ni aranse t’o lagbara
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 1-5 — Al-Fath
1إِنَّا فَتَحْنَا لَكَ فَتْحًا مُّبِينًا
Dajudaju Awa fun o ni isegun ponnbele
2لِّيَغْفِرَ لَكَ اللَّهُ مَا تَقَدَّمَ مِن ذَنبِكَ وَمَا تَأَخَّرَ وَيُتِمَّ نِعْمَتَهُ عَلَيْكَ وَيَهْدِيَكَ صِرَاطًا مُّسْتَقِيمًا
nitori ki Allahu le saforijin ohun ti o siwaju ninu asise re ati ohun ti o keyin (ninu re), ati nitori ki O le sasepe idera Re le o lori ati nitori ki O le fi ese re rinle soju ona taara (’Islam)
3وَيَنصُرَكَ اللَّهُ نَصْرًا عَزِيزًا
ati nitori ki Allahu le saranse fun o ni aranse t’o lagbara
4هُوَ الَّذِي أَنزَلَ السَّكِينَةَ فِي قُلُوبِ الْمُؤْمِنِينَ لِيَزْدَادُوا إِيمَانًا مَّعَ إِيمَانِهِمْ ۗ وَلِلَّهِ جُنُودُ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ ۚ وَكَانَ اللَّهُ عَلِيمًا حَكِيمًا
Oun ni Eni ti O so ifayabale sinu okan awon onigbagbo ododo nitori ki won le lekun ni igbagbo si igbagbo won. Ti Allahu si ni awon omo ogun sanmo ati ile. Allahu si n je Onimo, Ologbon
5لِّيُدْخِلَ الْمُؤْمِنِينَ وَالْمُؤْمِنَاتِ جَنَّاتٍ تَجْرِي مِن تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ خَالِدِينَ فِيهَا وَيُكَفِّرَ عَنْهُمْ سَيِّئَاتِهِمْ ۚ وَكَانَ ذَٰلِكَ عِندَ اللَّهِ فَوْزًا عَظِيمًا
(O se bee fun won) nitori ki O le mu awon onigbagbo ododo lokunrin ati onigbagbo ododo lobinrin wo inu awon Ogba Idera, eyi ti awon odo n san ni isale re, olusegbere ni won ninu re, ati nitori ki O le pa awon asise won re. Iyen si je erenje nla ni odo Allahu
Al-FathAtokọ Kurani
29Ẹsẹ
MedinanRevelation
3Ẹsẹ
Itumọ — Al-Fath 3
Surah Al-Fath Ẹsẹ 3 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : ati nitori ki Allahu le saranse fun o ni aranse…Surah Ẹsẹ 3/29 — Al-Fath الفتح (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Fath Gbọ, Al-Fath Itumọ, Al-Fath mp3, Al-Fath pdf. Ẹsẹ 1–5. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








