Al-Jumu'ah · 9/11
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Jumu'ah
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا إِذَا نُودِيَ لِلصَّلَاةِ مِن يَوْمِ الْجُمُعَةِ فَاسْعَوْا إِلَىٰ ذِكْرِ اللَّهِ وَذَرُوا الْبَيْعَ ۚ ذَٰلِكُمْ خَيْرٌ لَّكُمْ إِن كُنتُمْ تَعْلَمُونَ ۝٩
Yaaa ayyuhal lazeena aamanoo izaa noodiya lis-Salaati miny yawmil Jumu`ati fas`aw ilaa zikril laahi wa zarul bai`; zaalikum khayrul lakum in kuntum ta`lamoon
📖 Ni Yorùbá
Eyin ti e gbagbo ni ododo, nigba ti won ba pe irun ni ojo Jum‘ah, e yara lo sibi iranti Allahu, ki e si pa kata-kara ti. Iyen loore julo fun yin ti e ba mo
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 7-11 — Al-Jumu'ah

7وَلَا يَتَمَنَّوْنَهُ أَبَدًا بِمَا قَدَّمَتْ أَيْدِيهِمْ ۚ وَاللَّهُ عَلِيمٌ بِالظَّالِمِينَ
Won ko nii toro re laelae nitori ohun ti owo won ti ti siwaju. Allahu si ni Onimo nipa awon alabosi
8قُلْ إِنَّ الْمَوْتَ الَّذِي تَفِرُّونَ مِنْهُ فَإِنَّهُ مُلَاقِيكُمْ ۖ ثُمَّ تُرَدُّونَ إِلَىٰ عَالِمِ الْغَيْبِ وَالشَّهَادَةِ فَيُنَبِّئُكُم بِمَا كُنتُمْ تَعْمَلُونَ
So pe: "Dajudaju iku ti e n sa fun, dajudaju o maa pade yin. Leyin naa, won yoo da yin pada si odo Onimo-ikoko ati gbangba. O si maa fun yin ni iro ohun ti e n se nise
9يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا إِذَا نُودِيَ لِلصَّلَاةِ مِن يَوْمِ الْجُمُعَةِ فَاسْعَوْا إِلَىٰ ذِكْرِ اللَّهِ وَذَرُوا الْبَيْعَ ۚ ذَٰلِكُمْ خَيْرٌ لَّكُمْ إِن كُنتُمْ تَعْلَمُونَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, nigba ti won ba pe irun ni ojo Jum‘ah, e yara lo sibi iranti Allahu, ki e si pa kata-kara ti. Iyen loore julo fun yin ti e ba mo
10فَإِذَا قُضِيَتِ الصَّلَاةُ فَانتَشِرُوا فِي الْأَرْضِ وَابْتَغُوا مِن فَضْلِ اللَّهِ وَاذْكُرُوا اللَّهَ كَثِيرًا لَّعَلَّكُمْ تُفْلِحُونَ
Nigba ti won ba si pari irun, e tuka si ori ile, ki e si maa wa ninu oore Allahu. E ranti Allahu ni opolopo nitori ki e le jere
11وَإِذَا رَأَوْا تِجَارَةً أَوْ لَهْوًا انفَضُّوا إِلَيْهَا وَتَرَكُوكَ قَائِمًا ۚ قُلْ مَا عِندَ اللَّهِ خَيْرٌ مِّنَ اللَّهْوِ وَمِنَ التِّجَارَةِ ۚ وَاللَّهُ خَيْرُ الرَّازِقِينَ
Nigba ti won ba ri oja kan tabi iranu kan, won yoo da lo sibe. Won yo si fi o sile lori iduro. So pe: "Nnkan ti o wa ni odo Allahu l’oore ju iranu ati oja lo. Allahu si l’oore julo ninu awon olupese
Al-Jumu'ahAtokọ Kurani
11Ẹsẹ
MedinanRevelation
9Ẹsẹ

Itumọ — Al-Jumu'ah 9

Surah Al-Jumu'ah Ẹsẹ 9 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Eyin ti e gbagbo ni ododo, nigba ti won ba…

Surah Ẹsẹ 9/11 — Al-Jumu'ah الجمعة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Jumu'ah Gbọ, Al-Jumu'ah Itumọ, Al-Jumu'ah mp3, Al-Jumu'ah pdf. Ẹsẹ 7–11. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers