At-Taghabun · 15/18
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah At-Taghabun
إِنَّمَا أَمْوَالُكُمْ وَأَوْلَادُكُمْ فِتْنَةٌ ۚ وَاللَّهُ عِندَهُ أَجْرٌ عَظِيمٌ ۝١٥
Innamaa amwaalukum wa awlaadukum fitnah; wallaahu `indahooo ajrun `azeem
📖 Ni Yorùbá
Ifooro ni awon dukia yin ati awon omo yin. Allahu si ni esan nla wa ni odo Re

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 13-17 — Surah At-Taghabun

13اللَّهُ لَا إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ ۚ وَعَلَى اللَّهِ فَلْيَتَوَكَّلِ الْمُؤْمِنُونَ
Allahu, ko si olohun ti ijosin to si afi Oun. Allahu si ni ki awon onigbagbo ododo gbarale
14يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا إِنَّ مِنْ أَزْوَاجِكُمْ وَأَوْلَادِكُمْ عَدُوًّا لَّكُمْ فَاحْذَرُوهُمْ ۚ وَإِن تَعْفُوا وَتَصْفَحُوا وَتَغْفِرُوا فَإِنَّ اللَّهَ غَفُورٌ رَّحِيمٌ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, dajudaju ota wa fun yin ninu awon iyawo yin ati awon omo yin. Nitori naa, e sora fun won. Ti e ba samojukuro, ti e safojufo, ti e si saforijin (fun won), dajudaju Allahu ni Alaforijin, Asake-orun
15إِنَّمَا أَمْوَالُكُمْ وَأَوْلَادُكُمْ فِتْنَةٌ ۚ وَاللَّهُ عِندَهُ أَجْرٌ عَظِيمٌ
Ifooro ni awon dukia yin ati awon omo yin. Allahu si ni esan nla wa ni odo Re
16فَاتَّقُوا اللَّهَ مَا اسْتَطَعْتُمْ وَاسْمَعُوا وَأَطِيعُوا وَأَنفِقُوا خَيْرًا لِّأَنفُسِكُمْ ۗ وَمَن يُوقَ شُحَّ نَفْسِهِ فَأُولَٰئِكَ هُمُ الْمُفْلِحُونَ
Nitori naa, e beru Allahu bi e ba se lagbara mo. E gbo oro (Allahu), e tele e, ki e si nawo (fun esin Re) loore julo fun emi yin. Enikeni ti A ba so nibi ahun ati okanjua inu emi re, awon wonyen, awon ni olujere
17إِن تُقْرِضُوا اللَّهَ قَرْضًا حَسَنًا يُضَاعِفْهُ لَكُمْ وَيَغْفِرْ لَكُمْ ۚ وَاللَّهُ شَكُورٌ حَلِيمٌ
Ti e ba ya Allahu ni dukia t’o dara, O maa sadipele re fun yin. O si maa forijin yin. Allahu si ni Olumoore, Alafarada
At-TaghabunAtokọ Kurani
18Ẹsẹ
MedinanRevelation
15Ẹsẹ

Itumọ — At-Taghabun 15

Surah At-Taghabun Ẹsẹ 15 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ifooro ni awon dukia yin ati awon omo yin. Allahu…

Surah Ẹsẹ 15/18 — Surah At-Taghabun التغابن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah At-Taghabun Gbọ, Surah At-Taghabun Itumọ, Surah At-Taghabun mp3, Surah At-Taghabun pdf. Ẹsẹ 13–17. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers