At-Taghabun · 14/18
Itumọ Aṣẹ ohun — At-Taghabun
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا إِنَّ مِنْ أَزْوَاجِكُمْ وَأَوْلَادِكُمْ عَدُوًّا لَّكُمْ فَاحْذَرُوهُمْ ۚ وَإِن تَعْفُوا وَتَصْفَحُوا وَتَغْفِرُوا فَإِنَّ اللَّهَ غَفُورٌ رَّحِيمٌ ١٤
Transliteration
Yaaa ayyuhal lazeena aamanooo inna min azwaaji kum wa awlaadikum `aduwwal lakum fahzaroohum; wa in ta`foo wa tasfahoo wa taghfiroo fa innal laaha ghafoorur Raheem
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Eyin ti e gbagbo ni ododo, dajudaju ota wa fun yin ninu awon iyawo yin ati awon omo yin. Nitori naa, e sora fun won. Ti e ba samojukuro, ti e safojufo, ti e si saforijin (fun won), dajudaju Allahu ni Alaforijin, Asake-orun
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 12-16 — At-Taghabun
12وَأَطِيعُوا اللَّهَ وَأَطِيعُوا الرَّسُولَ ۚ فَإِن تَوَلَّيْتُمْ فَإِنَّمَا عَلَىٰ رَسُولِنَا الْبَلَاغُ الْمُبِينُ
Ki e tele ti Allahu. Ki e si tele ti Ojise. Ti e ba gbunri, ise-jije ponnbele lojuse Ojise Wa
13اللَّهُ لَا إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ ۚ وَعَلَى اللَّهِ فَلْيَتَوَكَّلِ الْمُؤْمِنُونَ
Allahu, ko si olohun ti ijosin to si afi Oun. Allahu si ni ki awon onigbagbo ododo gbarale
14يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا إِنَّ مِنْ أَزْوَاجِكُمْ وَأَوْلَادِكُمْ عَدُوًّا لَّكُمْ فَاحْذَرُوهُمْ ۚ وَإِن تَعْفُوا وَتَصْفَحُوا وَتَغْفِرُوا فَإِنَّ اللَّهَ غَفُورٌ رَّحِيمٌ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, dajudaju ota wa fun yin ninu awon iyawo yin ati awon omo yin. Nitori naa, e sora fun won. Ti e ba samojukuro, ti e safojufo, ti e si saforijin (fun won), dajudaju Allahu ni Alaforijin, Asake-orun
15إِنَّمَا أَمْوَالُكُمْ وَأَوْلَادُكُمْ فِتْنَةٌ ۚ وَاللَّهُ عِندَهُ أَجْرٌ عَظِيمٌ
Ifooro ni awon dukia yin ati awon omo yin. Allahu si ni esan nla wa ni odo Re
16فَاتَّقُوا اللَّهَ مَا اسْتَطَعْتُمْ وَاسْمَعُوا وَأَطِيعُوا وَأَنفِقُوا خَيْرًا لِّأَنفُسِكُمْ ۗ وَمَن يُوقَ شُحَّ نَفْسِهِ فَأُولَٰئِكَ هُمُ الْمُفْلِحُونَ
Nitori naa, e beru Allahu bi e ba se lagbara mo. E gbo oro (Allahu), e tele e, ki e si nawo (fun esin Re) loore julo fun emi yin. Enikeni ti A ba so nibi ahun ati okanjua inu emi re, awon wonyen, awon ni olujere
At-TaghabunAtokọ Kurani
18Ẹsẹ
MedinanRevelation
14Ẹsẹ
Itumọ — At-Taghabun 14
Surah At-Taghabun Ẹsẹ 14 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Eyin ti e gbagbo ni ododo, dajudaju ota wa fun…Surah Ẹsẹ 14/18 — At-Taghabun التغابن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: At-Taghabun Gbọ, At-Taghabun Itumọ, At-Taghabun mp3, At-Taghabun pdf. Ẹsẹ 12–16. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








