At-Taghabun · 16/18
Itumọ Aṣẹ ohun — At-Taghabun
فَاتَّقُوا اللَّهَ مَا اسْتَطَعْتُمْ وَاسْمَعُوا وَأَطِيعُوا وَأَنفِقُوا خَيْرًا لِّأَنفُسِكُمْ ۗ وَمَن يُوقَ شُحَّ نَفْسِهِ فَأُولَٰئِكَ هُمُ الْمُفْلِحُونَ ۝١٦
Fattaqul laaha mastat`tum wasma`oo wa atee`oo waanfiqoo khairal li anfusikum; wa many-yooqa shuha nafsihee fa-ulaaa`ika humul muflihoon
📖 Ni Yorùbá
Nitori naa, e beru Allahu bi e ba se lagbara mo. E gbo oro (Allahu), e tele e, ki e si nawo (fun esin Re) loore julo fun emi yin. Enikeni ti A ba so nibi ahun ati okanjua inu emi re, awon wonyen, awon ni olujere
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 14-18 — At-Taghabun

14يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا إِنَّ مِنْ أَزْوَاجِكُمْ وَأَوْلَادِكُمْ عَدُوًّا لَّكُمْ فَاحْذَرُوهُمْ ۚ وَإِن تَعْفُوا وَتَصْفَحُوا وَتَغْفِرُوا فَإِنَّ اللَّهَ غَفُورٌ رَّحِيمٌ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, dajudaju ota wa fun yin ninu awon iyawo yin ati awon omo yin. Nitori naa, e sora fun won. Ti e ba samojukuro, ti e safojufo, ti e si saforijin (fun won), dajudaju Allahu ni Alaforijin, Asake-orun
15إِنَّمَا أَمْوَالُكُمْ وَأَوْلَادُكُمْ فِتْنَةٌ ۚ وَاللَّهُ عِندَهُ أَجْرٌ عَظِيمٌ
Ifooro ni awon dukia yin ati awon omo yin. Allahu si ni esan nla wa ni odo Re
16فَاتَّقُوا اللَّهَ مَا اسْتَطَعْتُمْ وَاسْمَعُوا وَأَطِيعُوا وَأَنفِقُوا خَيْرًا لِّأَنفُسِكُمْ ۗ وَمَن يُوقَ شُحَّ نَفْسِهِ فَأُولَٰئِكَ هُمُ الْمُفْلِحُونَ
Nitori naa, e beru Allahu bi e ba se lagbara mo. E gbo oro (Allahu), e tele e, ki e si nawo (fun esin Re) loore julo fun emi yin. Enikeni ti A ba so nibi ahun ati okanjua inu emi re, awon wonyen, awon ni olujere
17إِن تُقْرِضُوا اللَّهَ قَرْضًا حَسَنًا يُضَاعِفْهُ لَكُمْ وَيَغْفِرْ لَكُمْ ۚ وَاللَّهُ شَكُورٌ حَلِيمٌ
Ti e ba ya Allahu ni dukia t’o dara, O maa sadipele re fun yin. O si maa forijin yin. Allahu si ni Olumoore, Alafarada
18عَالِمُ الْغَيْبِ وَالشَّهَادَةِ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ
Onimo-ikoko ati gbangba, Alagbara, Ologbon
At-TaghabunAtokọ Kurani
18Ẹsẹ
MedinanRevelation
16Ẹsẹ

Itumọ — At-Taghabun 16

Surah At-Taghabun Ẹsẹ 16 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Nitori naa, e beru Allahu bi e ba se lagbara…

Surah Ẹsẹ 16/18 — At-Taghabun التغابن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: At-Taghabun Gbọ, At-Taghabun Itumọ, At-Taghabun mp3, At-Taghabun pdf. Ẹsẹ 14–18. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers