Al-Qalam · 34/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Qalam
إِنَّ لِلْمُتَّقِينَ عِندَ رَبِّهِمْ جَنَّاتِ النَّعِيمِ ۝٣٤
Inna lilmuttaqeena `inda rabbihim jannaatin na`eem
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju awon Ogba Idera wa fun awon oluberu lodo Oluwa won

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 32-36 — Al-Qalam

32عَسَىٰ رَبُّنَا أَن يُبْدِلَنَا خَيْرًا مِّنْهَا إِنَّا إِلَىٰ رَبِّنَا رَاغِبُونَ
O see se ki Oluwa wa fi eyi t’o dara ju eyi lo paaro re fun wa. Dajudaju odo Oluwa wa ni awa n rokan oore si
33كَذَٰلِكَ الْعَذَابُ ۖ وَلَعَذَابُ الْآخِرَةِ أَكْبَرُ ۚ لَوْ كَانُوا يَعْلَمُونَ
Bayen ni iya naa se ri (fun won). Iya orun si tobi julo, ti o ba je pe won mo
34إِنَّ لِلْمُتَّقِينَ عِندَ رَبِّهِمْ جَنَّاتِ النَّعِيمِ
Dajudaju awon Ogba Idera wa fun awon oluberu lodo Oluwa won
35أَفَنَجْعَلُ الْمُسْلِمِينَ كَالْمُجْرِمِينَ
Se A maa se awon musulumi bi (A se maa se) awon elese bi
36مَا لَكُمْ كَيْفَ تَحْكُمُونَ
Ki l’o n se yin ti e fi n dajo bayii na
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
34Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 34

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 34 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju awon Ogba Idera wa fun awon oluberu lodo Oluwa…

Surah Ẹsẹ 34/52 — Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Qalam Gbọ, Al-Qalam Itumọ, Al-Qalam mp3, Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 32–36. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers