Al-Qalam · 35/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Qalam
أَفَنَجْعَلُ الْمُسْلِمِينَ كَالْمُجْرِمِينَ ۝٣٥
Afanaj`alul muslimeena kalmujrimeen
📖 Ni Yorùbá
Se A maa se awon musulumi bi (A se maa se) awon elese bi
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 33-37 — Al-Qalam

33كَذَٰلِكَ الْعَذَابُ ۖ وَلَعَذَابُ الْآخِرَةِ أَكْبَرُ ۚ لَوْ كَانُوا يَعْلَمُونَ
Bayen ni iya naa se ri (fun won). Iya orun si tobi julo, ti o ba je pe won mo
34إِنَّ لِلْمُتَّقِينَ عِندَ رَبِّهِمْ جَنَّاتِ النَّعِيمِ
Dajudaju awon Ogba Idera wa fun awon oluberu lodo Oluwa won
35أَفَنَجْعَلُ الْمُسْلِمِينَ كَالْمُجْرِمِينَ
Se A maa se awon musulumi bi (A se maa se) awon elese bi
36مَا لَكُمْ كَيْفَ تَحْكُمُونَ
Ki l’o n se yin ti e fi n dajo bayii na
37أَمْ لَكُمْ كِتَابٌ فِيهِ تَدْرُسُونَ
Tabi tira kan wa fun yin ti e n kekoo ninu re
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
35Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 35

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 35 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Se A maa se awon musulumi bi (A se maa…

Surah Ẹsẹ 35/52 — Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Qalam Gbọ, Al-Qalam Itumọ, Al-Qalam mp3, Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 33–37. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers