Al-A'raf · 27/206
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-A'raf
يَا بَنِي آدَمَ لَا يَفْتِنَنَّكُمُ الشَّيْطَانُ كَمَا أَخْرَجَ أَبَوَيْكُم مِّنَ الْجَنَّةِ يَنزِعُ عَنْهُمَا لِبَاسَهُمَا لِيُرِيَهُمَا سَوْآتِهِمَا ۗ إِنَّهُ يَرَاكُمْ هُوَ وَقَبِيلُهُ مِنْ حَيْثُ لَا تَرَوْنَهُمْ ۗ إِنَّا جَعَلْنَا الشَّيَاطِينَ أَوْلِيَاءَ لِلَّذِينَ لَا يُؤْمِنُونَ ۝٢٧
Yaa Banee Aadama laa yaftinannnakumush Shaitaanu kamaaa akhraja abawaikum minal Jannati yanzi`u `anhumaa libaasahumaa liyuriyahumaa saw aatihimaaa; innahoo yaraakum huwa wa qabeeluhoo min haisu laa tarawnahum; innaa ja`alnash Shayaateena awliyaaa`a lillazeena laa yu`minoon
📖 Ni Yorùbá
Omo (Anabi) Adam, e ma se je ki Esu ko ifooro ba yin gege bi o se yo awon obi yin mejeeji jade kuro ninu Ogba Idera. O gba aso kuro lara awon mejeeji nitori ki o le fi ihoho won han won. Dajudaju o n ri yin; oun ati awon omo ogun re (n ri yin) ni aye ti eyin ko ti ri won. Dajudaju Awa fi Esu se ore fun awon ti ko gbagbo

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 25-29 — Surah Al-A'raf

25قَالَ فِيهَا تَحْيَوْنَ وَفِيهَا تَمُوتُونَ وَمِنْهَا تُخْرَجُونَ
(Allahu) so pe: “Lori ile ni eyin yoo ti maa semi, lori re ni eyin yoo maa ku si, A o si mu yin jade lati inu re.”
26يَا بَنِي آدَمَ قَدْ أَنزَلْنَا عَلَيْكُمْ لِبَاسًا يُوَارِي سَوْآتِكُمْ وَرِيشًا ۖ وَلِبَاسُ التَّقْوَىٰ ذَٰلِكَ خَيْرٌ ۚ ذَٰلِكَ مِنْ آيَاتِ اللَّهِ لَعَلَّهُمْ يَذَّكَّرُونَ
Omo (Anabi) Adam, dajudaju A ti so aso kale fun yin, ti o maa bo ihoho yin ati ohun amusoro. Aso iberu Allahu, iyen l’o si loore julo. Iyen wa ninu awon ami Allahu nitori ki won le lo iranti
27يَا بَنِي آدَمَ لَا يَفْتِنَنَّكُمُ الشَّيْطَانُ كَمَا أَخْرَجَ أَبَوَيْكُم مِّنَ الْجَنَّةِ يَنزِعُ عَنْهُمَا لِبَاسَهُمَا لِيُرِيَهُمَا سَوْآتِهِمَا ۗ إِنَّهُ يَرَاكُمْ هُوَ وَقَبِيلُهُ مِنْ حَيْثُ لَا تَرَوْنَهُمْ ۗ إِنَّا جَعَلْنَا الشَّيَاطِينَ أَوْلِيَاءَ لِلَّذِينَ لَا يُؤْمِنُونَ
Omo (Anabi) Adam, e ma se je ki Esu ko ifooro ba yin gege bi o se yo awon obi yin mejeeji jade kuro ninu Ogba Idera. O gba aso kuro lara awon mejeeji nitori ki o le fi ihoho won han won. Dajudaju o n ri yin; oun ati awon omo ogun re (n ri yin) ni aye ti eyin ko ti ri won. Dajudaju Awa fi Esu se ore fun awon ti ko gbagbo
28وَإِذَا فَعَلُوا فَاحِشَةً قَالُوا وَجَدْنَا عَلَيْهَا آبَاءَنَا وَاللَّهُ أَمَرَنَا بِهَا ۗ قُلْ إِنَّ اللَّهَ لَا يَأْمُرُ بِالْفَحْشَاءِ ۖ أَتَقُولُونَ عَلَى اللَّهِ مَا لَا تَعْلَمُونَ
Nigba ti won ba si se ibaje kan, won a wi pe: "A ba awon baba wa lori re ni. Allahu l’O si pa a lase fun wa." So pe: "Dajudaju Allahu ki i p’ase ibaje. Se e fe safiti ohun ti e o nimo nipa re sodo Allahu ni
29قُلْ أَمَرَ رَبِّي بِالْقِسْطِ ۖ وَأَقِيمُوا وُجُوهَكُمْ عِندَ كُلِّ مَسْجِدٍ وَادْعُوهُ مُخْلِصِينَ لَهُ الدِّينَ ۚ كَمَا بَدَأَكُمْ تَعُودُونَ
So pe: “Oluwa mi p’ase sise deede. Ki e si doju yin ko (Allahu) ni gbogbo mosalasi. E pe E (ki e je) olusafomo-esin fun Un. Gege bi O se da yin (ti e fi di alaaye), e maa pada (di alaaye leyin iku yin).”
Al-A'rafAtokọ Kurani
206Ẹsẹ
MeccanRevelation
27Ẹsẹ

Itumọ — Al-A'raf 27

Surah Al-A'raf Ẹsẹ 27 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Omo (Anabi) Adam, e ma se je ki Esu ko…

Surah Ẹsẹ 27/206 — Surah Al-A'raf الأعراف (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-A'raf Gbọ, Surah Al-A'raf Itumọ, Surah Al-A'raf mp3, Surah Al-A'raf pdf. Ẹsẹ 25–29. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers