Surah At-Tin ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah At-Tin pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (8 Ẹsẹ — مكية). At-Tin Gbọ, At-Tin Itumọ, At-Tin mp3, At-Tin pdf.

Ka ati Gbọ Surah At-Tin

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy
M Mahmoud Khalil Al-Husary
A Abdurrahman As-Sudais
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi
A Abdul Basit Abdul Samad
A Ali Al-Hudhaify
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy
A Abu Bakr Ash-Shaatree
M Muhammad Ayyoub
A Abdullah Basfar
A Abdullah Al-Juhani
M Maher Al Muaiqly
x1
وَالتِّينِ وَالزَّيْتُونِ ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
Allahu bura pelu eso tin ati eso zaetun
وَطُورِ سِينِينَ ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
O tun bura pelu apata Sinin
وَهَٰذَا الْبَلَدِ الْأَمِينِ ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
O tun bura pelu ilu ifayabale yii
لَقَدْ خَلَقْنَا الْإِنسَانَ فِي أَحْسَنِ تَقْوِيمٍ ۝٤
📖 Itumọ Ẹsẹ 4
Dajudaju A seda eniyan pelu irisi t’o dara julo
ثُمَّ رَدَدْنَاهُ أَسْفَلَ سَافِلِينَ ۝٥
📖 Itumọ Ẹsẹ 5
Leyin naa, A maa da a pada si isale patapata (ninu Ina)
إِلَّا الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ فَلَهُمْ أَجْرٌ غَيْرُ مَمْنُونٍ ۝٦
📖 Itumọ Ẹsẹ 6
Ayafi awon t’o gbagbo ni ododo, ti won si se awon ise rere. Nitori naa, esan ti ko nii pin (ti ko nii pedin) n be fun won
فَمَا يُكَذِّبُكَ بَعْدُ بِالدِّينِ ۝٧
📖 Itumọ Ẹsẹ 7
Ta l’o tun n pe o ni opuro nipa Ojo esan leyin (oro yii)
أَلَيْسَ اللَّهُ بِأَحْكَمِ الْحَاكِمِينَ ۝٨
📖 Itumọ Ẹsẹ 8
Se Allahu ko ni Eni t’O mo ejo da julo ninu awon adajo ni
← 94 At-Tin (95/114) 96 →
Kika Surah At-Tin ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

95التين At-Tin 📚 8 Ẹsẹ مكية

Ẹsẹ kọọkan – Surah At-Tin — 8 Ẹsẹ




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers