An-Nur · 6/64
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah An-Nur
وَالَّذِينَ يَرْمُونَ أَزْوَاجَهُمْ وَلَمْ يَكُن لَّهُمْ شُهَدَاءُ إِلَّا أَنفُسُهُمْ فَشَهَادَةُ أَحَدِهِمْ أَرْبَعُ شَهَادَاتٍ بِاللَّهِ ۙ إِنَّهُ لَمِنَ الصَّادِقِينَ ٦
Transliteration
Wallazeena yarmoona azwaajahum wa lam yakul lahum shuhadaaa`u illaaa anfusuhum fashahaadatu ahadihim arb`u shahaadaatim billaahi innahoo laminas saadiqeen
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Awon t’o n fi esun sina kan awon iyawo won, ti ko si si elerii fun won afi awon funra won, eri eni kookan won ni ki o fi Allahu jerii ni ee merin pe dajudaju oun wa ninu awon olododo
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 4-8 — Surah An-Nur
4وَالَّذِينَ يَرْمُونَ الْمُحْصَنَاتِ ثُمَّ لَمْ يَأْتُوا بِأَرْبَعَةِ شُهَدَاءَ فَاجْلِدُوهُمْ ثَمَانِينَ جَلْدَةً وَلَا تَقْبَلُوا لَهُمْ شَهَادَةً أَبَدًا ۚ وَأُولَٰئِكَ هُمُ الْفَاسِقُونَ
Awon t’o n fi esun sina kan awon omoluabi lobinrin, leyin naa ti won ko mu awon elerii merin wa, e na won ni ogorin koboko. E ma se gba eri won mo laelae; awon wonyen si ni obileje
5إِلَّا الَّذِينَ تَابُوا مِن بَعْدِ ذَٰلِكَ وَأَصْلَحُوا فَإِنَّ اللَّهَ غَفُورٌ رَّحِيمٌ
Ayafi awon t’o ronu piwada leyin iyen, ti won si se atunse. Dajudaju Allahu ni Alaforijin, Asake-orun
6وَالَّذِينَ يَرْمُونَ أَزْوَاجَهُمْ وَلَمْ يَكُن لَّهُمْ شُهَدَاءُ إِلَّا أَنفُسُهُمْ فَشَهَادَةُ أَحَدِهِمْ أَرْبَعُ شَهَادَاتٍ بِاللَّهِ ۙ إِنَّهُ لَمِنَ الصَّادِقِينَ
Awon t’o n fi esun sina kan awon iyawo won, ti ko si si elerii fun won afi awon funra won, eri eni kookan won ni ki o fi Allahu jerii ni ee merin pe dajudaju oun wa ninu awon olododo
7وَالْخَامِسَةُ أَنَّ لَعْنَتَ اللَّهِ عَلَيْهِ إِن كَانَ مِنَ الْكَاذِبِينَ
Ee karun-un si ni pe ki ibi dandan Allahu maa ba oun, ti oun ba wa ninu awon opuro
8وَيَدْرَأُ عَنْهَا الْعَذَابَ أَن تَشْهَدَ أَرْبَعَ شَهَادَاتٍ بِاللَّهِ ۙ إِنَّهُ لَمِنَ الْكَاذِبِينَ
Ohun ti o maa ye iya fun iyawo ni pe ki o fi Allahu jerii ni ee merin pe dajudaju oko oun wa ninu awon opuro
An-NurAtokọ Kurani
64Ẹsẹ
MedinanRevelation
6Ẹsẹ
Itumọ — An-Nur 6
Surah An-Nur Ẹsẹ 6 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Awon t’o n fi esun sina kan awon iyawo won,…Surah Ẹsẹ 6/64 — Surah An-Nur النور (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah An-Nur Gbọ, Surah An-Nur Itumọ, Surah An-Nur mp3, Surah An-Nur pdf. Ẹsẹ 4–8. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Monday, September 7, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








