Al-Furqan · 74/77
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Furqan
وَالَّذِينَ يَقُولُونَ رَبَّنَا هَبْ لَنَا مِنْ أَزْوَاجِنَا وَذُرِّيَّاتِنَا قُرَّةَ أَعْيُنٍ وَاجْعَلْنَا لِلْمُتَّقِينَ إِمَامًا ٧٤
Transliteration
Wallazeena yaqooloona Rabbanaa hab lanaa min azwaajinaa wa zurriyaatinaa qurrata a`yuninw waj `alnaa lilmuttaqeena Imaamaa
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
(Awon ni) awon t’o n so pe: “Oluwa wa, ta wa ni ore itutu-oju lati ara awon iyawo wa ati awon omo wa. Ki O si se wa ni asiwaju fun awon oluberu (Re).”
M
Mishary Rashid Alafasy
✓
Mishary Rashid Alafasy
✓
M
Mahmoud Khalil Al-Husary
✓
Mahmoud Khalil Al-Husary
✓
A
Abdurrahman As-Sudais
✓
Abdurrahman As-Sudais
✓
M
Mohamed Siddiq Al-Minshawi
✓
Mohamed Siddiq Al-Minshawi
✓
A
Abdul Basit Abdul Samad
✓
Abdul Basit Abdul Samad
✓
A
Ali Al-Hudhaify
✓
Ali Al-Hudhaify
✓
A
Ahmed ibn Ali al-Ajamy
✓
Ahmed ibn Ali al-Ajamy
✓
A
Abu Bakr Ash-Shaatree
✓
Abu Bakr Ash-Shaatree
✓
M
Muhammad Ayyoub
✓
Muhammad Ayyoub
✓
A
Abdullah Basfar
✓
Abdullah Basfar
✓
A
Abdullah Al-Juhani
✓
Abdullah Al-Juhani
✓
M
Maher Al Muaiqly
✓
Maher Al Muaiqly
✓
0:00
0:00
📜 Ẹsẹ 72-76 — Surah Al-Furqan
72وَالَّذِينَ لَا يَشْهَدُونَ الزُّورَ وَإِذَا مَرُّوا بِاللَّغْوِ مَرُّوا كِرَامًا
(Awon ni) awon ti ko jerii eke. Ti won ba si koja nibi ibaje, won a koja pelu aponle
73وَالَّذِينَ إِذَا ذُكِّرُوا بِآيَاتِ رَبِّهِمْ لَمْ يَخِرُّوا عَلَيْهَا صُمًّا وَعُمْيَانًا
(Awon ni) awon ti o je pe ti won ba fi awon ayah Oluwa won seranti fun won, won ko da lule bi aditi ati afoju
74وَالَّذِينَ يَقُولُونَ رَبَّنَا هَبْ لَنَا مِنْ أَزْوَاجِنَا وَذُرِّيَّاتِنَا قُرَّةَ أَعْيُنٍ وَاجْعَلْنَا لِلْمُتَّقِينَ إِمَامًا
(Awon ni) awon t’o n so pe: “Oluwa wa, ta wa ni ore itutu-oju lati ara awon iyawo wa ati awon omo wa. Ki O si se wa ni asiwaju fun awon oluberu (Re).”
75أُولَٰئِكَ يُجْزَوْنَ الْغُرْفَةَ بِمَا صَبَرُوا وَيُلَقَّوْنَ فِيهَا تَحِيَّةً وَسَلَامًا
Awon wonyen, ipo giga (ninu Ogba Idera) ni A maa fi san won ni esan nitori pe won se suuru. Ikini ati sisalamo ni A oo fi maa pade won ninu re
76خَالِدِينَ فِيهَا ۚ حَسُنَتْ مُسْتَقَرًّا وَمُقَامًا
Olusegbere ni won ninu re. O dara ni ibugbe ati ibuduro
Al-FurqanAtokọ Kurani
77Ẹsẹ
MeccanRevelation
74Ẹsẹ
Itumọ — Al-Furqan 74
Surah Al-Furqan Ẹsẹ 74 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : (Awon ni) awon t’o n so pe: “Oluwa wa, ta…Surah Ẹsẹ 74/77 — Surah Al-Furqan الفرقان (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Furqan Gbọ, Surah Al-Furqan Itumọ, Surah Al-Furqan mp3, Surah Al-Furqan pdf. Ẹsẹ 72–76. Ni Yorùbá: العربية.
Surah Al-Furqan
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, September 29, 2026
Don't forget us in your sincere prayers


