Ash-Shu'ara · 22/227
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Ash-Shu'ara
وَتِلْكَ نِعْمَةٌ تَمُنُّهَا عَلَيَّ أَنْ عَبَّدتَّ بَنِي إِسْرَائِيلَ ۝٢٢
Wa tilka ni`matun tamun nuhaa `alaiya an `abbatta Baneee Israaa`eel
📖 Ni Yorùbá
Ati pe iyen ni idera ti o n se iregun re le mi lori. Pe o so awon omo ’Isro’il di eru (nko)

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 20-24 — Surah Ash-Shu'ara

20قَالَ فَعَلْتُهَا إِذًا وَأَنَا مِنَ الضَّالِّينَ
(Anabi Musa) so pe: "Mo se e nigba naa nigba ti mo wa ninu awon alaimokan ni
21فَفَرَرْتُ مِنكُمْ لَمَّا خِفْتُكُمْ فَوَهَبَ لِي رَبِّي حُكْمًا وَجَعَلَنِي مِنَ الْمُرْسَلِينَ
Mo si sa fun yin nigba ti mo beru yin. Nitori naa, Allahu ti ta mi lore ipo Anabi. O si se mi ni (okan) ninu awon Ojise
22وَتِلْكَ نِعْمَةٌ تَمُنُّهَا عَلَيَّ أَنْ عَبَّدتَّ بَنِي إِسْرَائِيلَ
Ati pe iyen ni idera ti o n se iregun re le mi lori. Pe o so awon omo ’Isro’il di eru (nko)
23قَالَ فِرْعَوْنُ وَمَا رَبُّ الْعَالَمِينَ
Fir‘aon wi pe: “Ki ni Oluwa gbogbo eda?”
24قَالَ رَبُّ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ وَمَا بَيْنَهُمَا ۖ إِن كُنتُم مُّوقِنِينَ
(Anabi Musa) so pe: “(Allahu ni)
Ash-Shu'araAtokọ Kurani
227Ẹsẹ
MeccanRevelation
22Ẹsẹ

Itumọ — Ash-Shu'ara 22

Surah Ash-Shu'ara Ẹsẹ 22 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ati pe iyen ni idera ti o n se iregun…

Surah Ẹsẹ 22/227 — Surah Ash-Shu'ara الشعراء (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Ash-Shu'ara Gbọ, Surah Ash-Shu'ara Itumọ, Surah Ash-Shu'ara mp3, Surah Ash-Shu'ara pdf. Ẹsẹ 20–24. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers