Aal-Imran · 137/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Aal-Imran
قَدْ خَلَتْ مِن قَبْلِكُمْ سُنَنٌ فَسِيرُوا فِي الْأَرْضِ فَانظُرُوا كَيْفَ كَانَ عَاقِبَةُ الْمُكَذِّبِينَ ۝١٣٧
Qad khalat min qablikum sunanum faseeroo fil ardi fanzuroo kaifa kaana `aaqiba tul mukazzibeen
📖 Ni Yorùbá
Awon oripa kan kuku ti lo siwaju yin. Nitori naa, e rin ile lo, ki e woye si bi igbeyin awon t’o pe ododo niro se ri

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 135-139 — Surah Aal-Imran

135وَالَّذِينَ إِذَا فَعَلُوا فَاحِشَةً أَوْ ظَلَمُوا أَنفُسَهُمْ ذَكَرُوا اللَّهَ فَاسْتَغْفَرُوا لِذُنُوبِهِمْ وَمَن يَغْفِرُ الذُّنُوبَ إِلَّا اللَّهُ وَلَمْ يُصِرُّوا عَلَىٰ مَا فَعَلُوا وَهُمْ يَعْلَمُونَ
Awon ti (o je pe) nigba ti won ba se ibaje kan tabi ti won ba sabosi si emi ara won, won a ranti Allahu, won a si toro aforijin fun ese won, - Ta si ni O n fori awon ese jin (eda) bi ko se Allahu. Won ko si taku sori ohun ti won se nigba ti won mo (pe ese ni)
136أُولَٰئِكَ جَزَاؤُهُم مَّغْفِرَةٌ مِّن رَّبِّهِمْ وَجَنَّاتٌ تَجْرِي مِن تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ خَالِدِينَ فِيهَا ۚ وَنِعْمَ أَجْرُ الْعَامِلِينَ
Awon wonyen, esan won lodo Oluwa won ni aforijin ati awon Ogba Idera kan ti awon odo n san ni isale re. Olusegbere ni won ninu re. Esan oluse-ise rere si dara
137قَدْ خَلَتْ مِن قَبْلِكُمْ سُنَنٌ فَسِيرُوا فِي الْأَرْضِ فَانظُرُوا كَيْفَ كَانَ عَاقِبَةُ الْمُكَذِّبِينَ
Awon oripa kan kuku ti lo siwaju yin. Nitori naa, e rin ile lo, ki e woye si bi igbeyin awon t’o pe ododo niro se ri
138هَٰذَا بَيَانٌ لِّلنَّاسِ وَهُدًى وَمَوْعِظَةٌ لِّلْمُتَّقِينَ
Eyi ni alaye fun awon eniyan. Imona ati waasi si ni fun awon oluberu (Allahu)
139وَلَا تَهِنُوا وَلَا تَحْزَنُوا وَأَنتُمُ الْأَعْلَوْنَ إِن كُنتُم مُّؤْمِنِينَ
E ma se kole, e si ma se banuje; eyin l’e maa leke ti e ba je onigbagbo ododo
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
137Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 137

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 137 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Awon oripa kan kuku ti lo siwaju yin. Nitori naa,…

Surah Ẹsẹ 137/200 — Surah Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Aal-Imran Gbọ, Surah Aal-Imran Itumọ, Surah Aal-Imran mp3, Surah Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 135–139. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, September 8, 2026

Don't forget us in your sincere prayers