Aal-Imran · 147/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Aal-Imran
وَمَا كَانَ قَوْلَهُمْ إِلَّا أَن قَالُوا رَبَّنَا اغْفِرْ لَنَا ذُنُوبَنَا وَإِسْرَافَنَا فِي أَمْرِنَا وَثَبِّتْ أَقْدَامَنَا وَانصُرْنَا عَلَى الْقَوْمِ الْكَافِرِينَ ۝١٤٧
Wa maa kaana qawlahum illaa an qaaloo Rabbanagh fir lanaa zunoobanaa wa israafanaa feee amirnaa wa sabbit aqdaamanaa wansurnaa `alal qawmil kaafireen
📖 Ni Yorùbá
Ko si si ohun kan ti won so tayo pe won so pe: "Oluwa wa fori awon ese wa ati aseju wa ninu oro wa jin wa, mu ese wa duro sinsin, ki O si se aranse fun wa lori ijo alaigbagbo
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 145-149 — Aal-Imran

145وَمَا كَانَ لِنَفْسٍ أَن تَمُوتَ إِلَّا بِإِذْنِ اللَّهِ كِتَابًا مُّؤَجَّلًا ۗ وَمَن يُرِدْ ثَوَابَ الدُّنْيَا نُؤْتِهِ مِنْهَا وَمَن يُرِدْ ثَوَابَ الْآخِرَةِ نُؤْتِهِ مِنْهَا ۚ وَسَنَجْزِي الشَّاكِرِينَ
Ko letoo fun emi kan lati ku afi pelu iyonda Allahu. (Iku je) akosile onigbedeke. Enikeni ti o ba n fe esan (ni) aye, A maa fun un ni aye. Enikeni ti o ba si n fe esan (ni) orun, A maa fun un ni orun. A o si san awon oludupe ni esan rere
146وَكَأَيِّن مِّن نَّبِيٍّ قَاتَلَ مَعَهُ رِبِّيُّونَ كَثِيرٌ فَمَا وَهَنُوا لِمَا أَصَابَهُمْ فِي سَبِيلِ اللَّهِ وَمَا ضَعُفُوا وَمَا اسْتَكَانُوا ۗ وَاللَّهُ يُحِبُّ الصَّابِرِينَ
Meloo meloo ninu awon Anabi ti won ti jagun esin pelu opolopo omo-eyin (won). Won ko ni irewesi okan nipa ohun ti o sele si won ni oju ogun esin Allahu. Won ko kole, won ko si jura won sile fun ota esin. Allahu si nifee awon onisuuru
147وَمَا كَانَ قَوْلَهُمْ إِلَّا أَن قَالُوا رَبَّنَا اغْفِرْ لَنَا ذُنُوبَنَا وَإِسْرَافَنَا فِي أَمْرِنَا وَثَبِّتْ أَقْدَامَنَا وَانصُرْنَا عَلَى الْقَوْمِ الْكَافِرِينَ
Ko si si ohun kan ti won so tayo pe won so pe: "Oluwa wa fori awon ese wa ati aseju wa ninu oro wa jin wa, mu ese wa duro sinsin, ki O si se aranse fun wa lori ijo alaigbagbo
148فَآتَاهُمُ اللَّهُ ثَوَابَ الدُّنْيَا وَحُسْنَ ثَوَابِ الْآخِرَةِ ۗ وَاللَّهُ يُحِبُّ الْمُحْسِنِينَ
Nitori naa, Allahu fun won ni esan aye ati daadaa esan orun. Allahu si nifee awon oluse rere
149يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا إِن تُطِيعُوا الَّذِينَ كَفَرُوا يَرُدُّوكُمْ عَلَىٰ أَعْقَابِكُمْ فَتَنقَلِبُوا خَاسِرِينَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, ti e ba tele awon t’o sai gbagbo, won maa yi yin lese pada kuro ninu esin. Nigba naa, e maa pada di eni ofo (sinu aigbagbo)
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
147Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 147

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 147 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ko si si ohun kan ti won so tayo pe…

Surah Ẹsẹ 147/200 — Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Aal-Imran Gbọ, Aal-Imran Itumọ, Aal-Imran mp3, Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 145–149. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers