Aal-Imran · 164/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Aal-Imran
لَقَدْ مَنَّ اللَّهُ عَلَى الْمُؤْمِنِينَ إِذْ بَعَثَ فِيهِمْ رَسُولًا مِّنْ أَنفُسِهِمْ يَتْلُو عَلَيْهِمْ آيَاتِهِ وَيُزَكِّيهِمْ وَيُعَلِّمُهُمُ الْكِتَابَ وَالْحِكْمَةَ وَإِن كَانُوا مِن قَبْلُ لَفِي ضَلَالٍ مُّبِينٍ ١٦٤
Transliteration
Laqad mannal laahu `alal mu`mineena iz ba`asa feehim Rasoolam min anfusihim yatloo `alaihim Aayaatihee wa yuzakkeehim wa yu`allimu humul Kitaaba wal Hikmata wa in kaanoo min qablu lafee dalaalim mubeen
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Allahu kuku ti se oore fun awon onigbagbo ododo nigba ti O fi le gbe Ojise kan dide si won laaarin ara won. (Ojise naa) n ke awon ayah Re fun won. O n fo won mo (ninu ese). O si n ko won ni Tira (al-Ƙur’an) ati ijinle oye (sunnah), bi o tile je pe teletele won wa ninu isina ponnbele
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 162-166 — Surah Aal-Imran
162أَفَمَنِ اتَّبَعَ رِضْوَانَ اللَّهِ كَمَن بَاءَ بِسَخَطٍ مِّنَ اللَّهِ وَمَأْوَاهُ جَهَنَّمُ ۚ وَبِئْسَ الْمَصِيرُ
Se eni ti o (sise) to iyonu Allahu da bi eni ti o pada wale pelu ibinu lati odo Allahu, ibugbe re si ni ina Jahanamo? Ikangun naa si buru
163هُمْ دَرَجَاتٌ عِندَ اللَّهِ ۗ وَاللَّهُ بَصِيرٌ بِمَا يَعْمَلُونَ
(Ekinni keji ero inu Ogba Idera ati ero inu Ina ni) won ni ipo (otooto) ni odo Allahu. Allahu si ni Oluriran nipa ohun ti won n se nise
164لَقَدْ مَنَّ اللَّهُ عَلَى الْمُؤْمِنِينَ إِذْ بَعَثَ فِيهِمْ رَسُولًا مِّنْ أَنفُسِهِمْ يَتْلُو عَلَيْهِمْ آيَاتِهِ وَيُزَكِّيهِمْ وَيُعَلِّمُهُمُ الْكِتَابَ وَالْحِكْمَةَ وَإِن كَانُوا مِن قَبْلُ لَفِي ضَلَالٍ مُّبِينٍ
Allahu kuku ti se oore fun awon onigbagbo ododo nigba ti O fi le gbe Ojise kan dide si won laaarin ara won. (Ojise naa) n ke awon ayah Re fun won. O n fo won mo (ninu ese). O si n ko won ni Tira (al-Ƙur’an) ati ijinle oye (sunnah), bi o tile je pe teletele won wa ninu isina ponnbele
165أَوَلَمَّا أَصَابَتْكُم مُّصِيبَةٌ قَدْ أَصَبْتُم مِّثْلَيْهَا قُلْتُمْ أَنَّىٰ هَٰذَا ۖ قُلْ هُوَ مِنْ عِندِ أَنفُسِكُمْ ۗ إِنَّ اللَّهَ عَلَىٰ كُلِّ شَيْءٍ قَدِيرٌ
Se gbogbo igba ti adanwo kan ba kan yin, ti e si ti fi meji iru re (kan awon keferi), ni eyin yoo maa so pe: “Ona wo ni eyi gba sele si wa?” So pe: “O wa lati odo ara yin.” Dajudaju Allahu ni Alagbara lori gbogbo nnkan
166وَمَا أَصَابَكُمْ يَوْمَ الْتَقَى الْجَمْعَانِ فَبِإِذْنِ اللَّهِ وَلِيَعْلَمَ الْمُؤْمِنِينَ
Ohun ti o sele si yin ni ojo ti iko ogun mejeeji pade (sele) pelu iyonda Allahu. Ati pe nitori ki O le safi han awon onigbagbo ododo ni
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
164Ẹsẹ
Itumọ — Aal-Imran 164
Surah Aal-Imran Ẹsẹ 164 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Allahu kuku ti se oore fun awon onigbagbo ododo nigba…Surah Ẹsẹ 164/200 — Surah Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Aal-Imran Gbọ, Surah Aal-Imran Itumọ, Surah Aal-Imran mp3, Surah Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 162–166. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Monday, September 7, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








