Aal-Imran · 31/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Aal-Imran
قُلْ إِن كُنتُمْ تُحِبُّونَ اللَّهَ فَاتَّبِعُونِي يُحْبِبْكُمُ اللَّهُ وَيَغْفِرْ لَكُمْ ذُنُوبَكُمْ ۗ وَاللَّهُ غَفُورٌ رَّحِيمٌ ۝٣١
Qul in kuntum tuhibboonal laaha fattabi` oonee yuhbibkumul laahu wa yaghfir lakum zunoobakum; wallaahu Ghafoorur Raheem
📖 Ni Yorùbá
So pe: “Ti eyin ba nifee Allahu, e tele mi, Allahu maa nifee yin, O si maa fori ese yin jin yin. Allahu ni Alaforijin, Asake-orun

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 29-33 — Aal-Imran

29قُلْ إِن تُخْفُوا مَا فِي صُدُورِكُمْ أَوْ تُبْدُوهُ يَعْلَمْهُ اللَّهُ ۗ وَيَعْلَمُ مَا فِي السَّمَاوَاتِ وَمَا فِي الْأَرْضِ ۗ وَاللَّهُ عَلَىٰ كُلِّ شَيْءٍ قَدِيرٌ
So pe: “Ti e ba fi ohun ti n be ninu okan yin pamo tabi e fi han, Allahu mo on. O si mo ohunkohun t’o wa ninu awon sanmo ati ohunkohun t’o wa ninu ile. Allahu si ni Alagbara lori gbogbo nnkan
30يَوْمَ تَجِدُ كُلُّ نَفْسٍ مَّا عَمِلَتْ مِنْ خَيْرٍ مُّحْضَرًا وَمَا عَمِلَتْ مِن سُوءٍ تَوَدُّ لَوْ أَنَّ بَيْنَهَا وَبَيْنَهُ أَمَدًا بَعِيدًا ۗ وَيُحَذِّرُكُمُ اللَّهُ نَفْسَهُ ۗ وَاللَّهُ رَءُوفٌ بِالْعِبَادِ
Ni ojo ti emi kookan yoo ri ohun ti o se ninu ise rere niwaju (re) ati ohun ti o se ninu ise ibi, o maa fe ki akoko t’o jinna wa laaarin oun ati ise ibi re. Allahu si n kilo ara Re fun yin. Allahu si ni Alaaanu awon olujosin
31قُلْ إِن كُنتُمْ تُحِبُّونَ اللَّهَ فَاتَّبِعُونِي يُحْبِبْكُمُ اللَّهُ وَيَغْفِرْ لَكُمْ ذُنُوبَكُمْ ۗ وَاللَّهُ غَفُورٌ رَّحِيمٌ
So pe: “Ti eyin ba nifee Allahu, e tele mi, Allahu maa nifee yin, O si maa fori ese yin jin yin. Allahu ni Alaforijin, Asake-orun
32قُلْ أَطِيعُوا اللَّهَ وَالرَّسُولَ ۖ فَإِن تَوَلَّوْا فَإِنَّ اللَّهَ لَا يُحِبُّ الْكَافِرِينَ
So pe: “E tele (ti) Allahu ati Ojise. Ti e ba si peyin da, dajudaju Allahu ko nifee awon alaigbagbo
33۞ إِنَّ اللَّهَ اصْطَفَىٰ آدَمَ وَنُوحًا وَآلَ إِبْرَاهِيمَ وَآلَ عِمْرَانَ عَلَى الْعَالَمِينَ
Dajudaju Allahu sa Adam, Nuh, ara ile ’Ibrohim ati ara ile ‘Imron lesa lori awon eda (asiko tiwon)
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
31Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 31

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 31 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : So pe: “Ti eyin ba nifee Allahu, e tele mi,…

Surah Ẹsẹ 31/200 — Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Aal-Imran Gbọ, Aal-Imran Itumọ, Aal-Imran mp3, Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 29–33. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers