Al-An'am · 6/165
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-An'am
أَلَمْ يَرَوْا كَمْ أَهْلَكْنَا مِن قَبْلِهِم مِّن قَرْنٍ مَّكَّنَّاهُمْ فِي الْأَرْضِ مَا لَمْ نُمَكِّن لَّكُمْ وَأَرْسَلْنَا السَّمَاءَ عَلَيْهِم مِّدْرَارًا وَجَعَلْنَا الْأَنْهَارَ تَجْرِي مِن تَحْتِهِمْ فَأَهْلَكْنَاهُم بِذُنُوبِهِمْ وَأَنشَأْنَا مِن بَعْدِهِمْ قَرْنًا آخَرِينَ ۝٦
Alam yaraw kam ahlaknaa min qablihim min qarnim makkannaahum fil ardi maa lam numakkil lakum wa arsalnas samaaa`a `alaihim midraaranw wa ja`alnal anhaara tajree min tahtihim fa ahlak naahum bizunoobihim wa anshaanaa mim ba`dihim qarnan aakhareen
📖 Ni Yorùbá
Se won ko ri i pe meloo meloo ninu awon iran ti A ti pare siwaju won? Awon ti A fun ni ipo lori ile, (iru) ipo ti A ko fun eyin. A si ro omi ojo pupo fun won lati sanmo. A si se awon odo ti n san si isale (ile) won. Leyin naa, A pa won re nitori ese won. A si da awon iran miiran leyin won
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 4-8 — Al-An'am

4وَمَا تَأْتِيهِم مِّنْ آيَةٍ مِّنْ آيَاتِ رَبِّهِمْ إِلَّا كَانُوا عَنْهَا مُعْرِضِينَ
Ko si ami kan ti o maa de ba won ninu awon ami Oluwa won, afi ki won maa gbunri kuro nibe
5فَقَدْ كَذَّبُوا بِالْحَقِّ لَمَّا جَاءَهُمْ ۖ فَسَوْفَ يَأْتِيهِمْ أَنبَاءُ مَا كَانُوا بِهِ يَسْتَهْزِئُونَ
Won kuku pe ododo niro nigba ti o de ba won. Nitori naa, laipe awon iro ohun ti won maa n fi se yeye n bo wa ba won
6أَلَمْ يَرَوْا كَمْ أَهْلَكْنَا مِن قَبْلِهِم مِّن قَرْنٍ مَّكَّنَّاهُمْ فِي الْأَرْضِ مَا لَمْ نُمَكِّن لَّكُمْ وَأَرْسَلْنَا السَّمَاءَ عَلَيْهِم مِّدْرَارًا وَجَعَلْنَا الْأَنْهَارَ تَجْرِي مِن تَحْتِهِمْ فَأَهْلَكْنَاهُم بِذُنُوبِهِمْ وَأَنشَأْنَا مِن بَعْدِهِمْ قَرْنًا آخَرِينَ
Se won ko ri i pe meloo meloo ninu awon iran ti A ti pare siwaju won? Awon ti A fun ni ipo lori ile, (iru) ipo ti A ko fun eyin. A si ro omi ojo pupo fun won lati sanmo. A si se awon odo ti n san si isale (ile) won. Leyin naa, A pa won re nitori ese won. A si da awon iran miiran leyin won
7وَلَوْ نَزَّلْنَا عَلَيْكَ كِتَابًا فِي قِرْطَاسٍ فَلَمَسُوهُ بِأَيْدِيهِمْ لَقَالَ الَّذِينَ كَفَرُوا إِنْ هَٰذَا إِلَّا سِحْرٌ مُّبِينٌ
Ti o ba je pe A so tira kan ti A ko sinu takada kale fun o, ki won si fi owo won gba a mu (bayii), dajudaju awon t’o sai gbagbo iba wi pe: “Ki ni eyi bi ko se idan ponnbele.”
8وَقَالُوا لَوْلَا أُنزِلَ عَلَيْهِ مَلَكٌ ۖ وَلَوْ أَنزَلْنَا مَلَكًا لَّقُضِيَ الْأَمْرُ ثُمَّ لَا يُنظَرُونَ
Won si wi pe: “Nitori ki ni Won ko se so molaika kan kale fun un?” Ti o ba je pe A so molaika kan kale, oro iba ti yanju. Leyin naa, A o si nii lo won lara mo
Al-An'amAtokọ Kurani
165Ẹsẹ
MeccanRevelation
6Ẹsẹ

Itumọ — Al-An'am 6

Surah Al-An'am Ẹsẹ 6 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Se won ko ri i pe meloo meloo ninu awon…

Surah Ẹsẹ 6/165 — Al-An'am الأنعام (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-An'am Gbọ, Al-An'am Itumọ, Al-An'am mp3, Al-An'am pdf. Ẹsẹ 4–8. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers