Al-A'raf · 205/206
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-A'raf
وَاذْكُر رَّبَّكَ فِي نَفْسِكَ تَضَرُّعًا وَخِيفَةً وَدُونَ الْجَهْرِ مِنَ الْقَوْلِ بِالْغُدُوِّ وَالْآصَالِ وَلَا تَكُن مِّنَ الْغَافِلِينَ ٢٠٥
Transliteration
Wazkur Rabbaka fee nafsika tadarru`anw wa kheefatanw wa doonal jahri minal qawli bilghuduwwi wal aasali wa laa takum minal ghaafileen
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Se iranti Oluwa Re ninu emi re pelu iraworase ati iberu (Allahu), ko si nii je oro ariwo, ni owuro ati asale. Iwo ko si gbodo wa ninu awon olugbagbera (nipa iranti Allahu)
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 203-206 — Surah Al-A'raf
203وَإِذَا لَمْ تَأْتِهِم بِآيَةٍ قَالُوا لَوْلَا اجْتَبَيْتَهَا ۚ قُلْ إِنَّمَا أَتَّبِعُ مَا يُوحَىٰ إِلَيَّ مِن رَّبِّي ۚ هَٰذَا بَصَائِرُ مِن رَّبِّكُمْ وَهُدًى وَرَحْمَةٌ لِّقَوْمٍ يُؤْمِنُونَ
Nigba ti o o ba mu ami wa ba won, won a wi pe: “Iwo ko se se adahun re?” So pe: “Ohun ti Won fi ranse si mi ni imisi lati odo Oluwa mi ni mo n tele. (al-Ƙur’an) yii si ni awon eri t’o daju lati odo Oluwa yin. Imona ati ike si ni fun awon ijo onigbagbo ododo
204وَإِذَا قُرِئَ الْقُرْآنُ فَاسْتَمِعُوا لَهُ وَأَنصِتُوا لَعَلَّكُمْ تُرْحَمُونَ
Nigba ti won ba n ke al-Ƙur’an, e teti si i, ki e si dake nitori ki A le ke yin
205وَاذْكُر رَّبَّكَ فِي نَفْسِكَ تَضَرُّعًا وَخِيفَةً وَدُونَ الْجَهْرِ مِنَ الْقَوْلِ بِالْغُدُوِّ وَالْآصَالِ وَلَا تَكُن مِّنَ الْغَافِلِينَ
Se iranti Oluwa Re ninu emi re pelu iraworase ati iberu (Allahu), ko si nii je oro ariwo, ni owuro ati asale. Iwo ko si gbodo wa ninu awon olugbagbera (nipa iranti Allahu)
206إِنَّ الَّذِينَ عِندَ رَبِّكَ لَا يَسْتَكْبِرُونَ عَنْ عِبَادَتِهِ وَيُسَبِّحُونَهُ وَلَهُ يَسْجُدُونَ ۩
Dajudaju awon t’o n be lodo Oluwa re, won ki i jora won loju lati josin fun Un. Won n safomo fun Un. Won si n fori kanle fun Un
Al-A'rafAtokọ Kurani
206Ẹsẹ
MeccanRevelation
205Ẹsẹ
Itumọ — Al-A'raf 205
Surah Al-A'raf Ẹsẹ 205 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Se iranti Oluwa Re ninu emi re pelu iraworase ati…Surah Ẹsẹ 205/206 — Surah Al-A'raf الأعراف (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-A'raf Gbọ, Surah Al-A'raf Itumọ, Surah Al-A'raf mp3, Surah Al-A'raf pdf. Ẹsẹ 203–206. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, September 8, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








