Nuh · 24/28
Itumọ Aṣẹ ohun — Nuh
وَقَدْ أَضَلُّوا كَثِيرًا ۖ وَلَا تَزِدِ الظَّالِمِينَ إِلَّا ضَلَالًا ۝٢٤
Wa qad adalloo kasee ranw wa laa tazidiz zaalimeena illaa dalaalaa
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju won ti ko opolopo sina. (Oluwa mi) ma se je ki awon alabosi lekun ni kini kan bi ko se isina
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 22-26 — Nuh

22وَمَكَرُوا مَكْرًا كُبَّارًا
Won si dete ni ete t’o tobi
23وَقَالُوا لَا تَذَرُنَّ آلِهَتَكُمْ وَلَا تَذَرُنَّ وَدًّا وَلَا سُوَاعًا وَلَا يَغُوثَ وَيَعُوقَ وَنَسْرًا
Won si wi pe: "E ma se fi awon orisa yin sile. E ma se fi orisa Wadd, Suwa‘u, Yeguth, Ye‘uƙ ati Nasr sile
24وَقَدْ أَضَلُّوا كَثِيرًا ۖ وَلَا تَزِدِ الظَّالِمِينَ إِلَّا ضَلَالًا
Dajudaju won ti ko opolopo sina. (Oluwa mi) ma se je ki awon alabosi lekun ni kini kan bi ko se isina
25مِّمَّا خَطِيئَاتِهِمْ أُغْرِقُوا فَأُدْخِلُوا نَارًا فَلَمْ يَجِدُوا لَهُم مِّن دُونِ اللَّهِ أَنصَارًا
Nitori ese won, won te won ri sinu omi. Won si maa fi won sinu Ina. Won ko si nii ri awon alaranse fun won leyin Allahu
26وَقَالَ نُوحٌ رَّبِّ لَا تَذَرْ عَلَى الْأَرْضِ مِنَ الْكَافِرِينَ دَيَّارًا
(Anabi) Nuh tun so pe: "Oluwa mi, ma se fi eni kan kan ninu awon alaigbagbo sile lori ile
NuhAtokọ Kurani
28Ẹsẹ
MeccanRevelation
24Ẹsẹ

Itumọ — Nuh 24

Surah Nuh Ẹsẹ 24 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju won ti ko opolopo sina. (Oluwa mi) ma se…

Surah Ẹsẹ 24/28 — Nuh نوح (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Nuh Gbọ, Nuh Itumọ, Nuh mp3, Nuh pdf. Ẹsẹ 22–26. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers