Al-Muzzammil · 19/20
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Muzzammil
إِنَّ هَٰذِهِۦ تَذۡكِرَةٌۖ فَمَن شَآءَ ٱتَّخَذَ إِلَىٰ رَبِّهِۦ سَبِيلًا  ۝١٩
Inna haazihee tazkiratun fa man shaaa`at takhaza ilaa Rabbihee sabeelaa
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju eyi ni iranti. Nitori naa, eni ti o ba fe ki o mu oju ona kan to de odo Oluwa re
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 17-20 — Al-Muzzammil

17فَكَيۡفَ تَتَّقُونَ إِن كَفَرۡتُمۡ يَوۡمًا يَجۡعَلُ ٱلۡوِلۡدَٰنَ شِيبًا 
Ti eyin ba sai gbagbo, bawo ni eyin yoo se beru ojo kan t’o maa mu awon omode hewu
18ٱلسَّمَآءُ مُنفَطِرُۢ بِهِۦۚ كَانَ وَعۡدُهُۥ مَفۡعُولًا 
Sanmo si maa faya perepere ninu re. Adehun Re je ohun ti o maa se
19إِنَّ هَٰذِهِۦ تَذۡكِرَةٌۖ فَمَن شَآءَ ٱتَّخَذَ إِلَىٰ رَبِّهِۦ سَبِيلًا 
Dajudaju eyi ni iranti. Nitori naa, eni ti o ba fe ki o mu oju ona kan to de odo Oluwa re
20۞ إِنَّ رَبَّكَ يَعۡلَمُ أَنَّكَ تَقُومُ أَدۡنَىٰ مِن ثُلُثَيِ ٱلَّيۡلِ وَنِصۡفَهُۥ وَثُلُثَهُۥ وَطَآئِفَةٌ مِّنَ ٱلَّذِينَ مَعَكَۚ وَٱللَّهُ يُقَدِّرُ ٱلَّيۡلَ وَٱلنَّهَارَۚ عَلِمَ أَن لَّن تُحۡصُوهُ فَتَابَ عَلَيۡكُمۡۖ فَٱقۡرَءُواْ مَا تَيَسَّرَ مِنَ ٱلۡقُرۡءَانِۚ عَلِمَ أَن سَيَكُونُ مِنكُم مَّرۡضَىٰ وَءَاخَرُونَ يَضۡرِبُونَ فِي ٱلۡأَرۡضِ يَبۡتَغُونَ مِن فَضۡلِ ٱللَّهِ وَءَاخَرُونَ يُقَٰتِلُونَ فِي سَبِيلِ ٱللَّهِۖ فَٱقۡرَءُواْ مَا تَيَسَّرَ مِنۡهُۚ وَأَقِيمُواْ ٱلصَّلَوٰةَ وَءَاتُواْ ٱلزَّكَوٰةَ وَأَقۡرِضُواْ ٱللَّهَ قَرۡضًا حَسَنًاۚ وَمَا تُقَدِّمُواْ لِأَنفُسِكُم مِّنۡ خَيۡرٍ تَجِدُوهُ عِندَ ٱللَّهِ هُوَ خَيۡرًا وَأَعۡظَمَ أَجۡرًاۚ وَٱسۡتَغۡفِرُواْ ٱللَّهَۖ إِنَّ ٱللَّهَ غَفُورٌ رَّحِيمُۢ 
Dajudaju Oluwa re mo pe dajudaju iwo n dide kirun fun ohun t’o kere si ilata meji oru tabi ilaji re tabi ilata re. Igun kan ninu awon t’o wa pelu re (naa n se bee). Allahu l’O n sodiwon oru ati osan. O si mo pe e ko le so o. Nitori naa, O ti da a pada si fifuye fun yin. Nitori naa, e ke ohun ti o ba rorun (fun yin) ninu al-Ƙur’an. O mo pe awon alaisan yoo wa ninu yin. Awon miiran si n ririn ajo lori-ile, ti won n wa ninu oore Allahu. Awon miiran si n jagun fun esin Allahu. Nitori naa, e ke ohun ti o ba rorun (fun yin) ninu re. E kirun (oran-an-yan). E yo Zakah. Ki e si ya Allahu ni dukia t’o dara. Ohunkohun ti e ba ti siwaju fun emi ara yin ninu ohun rere, eyin yoo ba a lodo Allahu ni ohun rere ati ni ohun ti o tobi julo ni esan. E toro aforijin lodo Allahu. Dajudaju Allahu ni Alaforijin, Asake-orun
Al-MuzzammilAtokọ Kurani
20Ẹsẹ
MeccanRevelation
19Ẹsẹ

Itumọ — Al-Muzzammil 19

Surah Ẹsẹ 19/20 — Al-Muzzammil المزمل (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Muzzammil Gbọ, Al-Muzzammil Itumọ, Al-Muzzammil mp3, Al-Muzzammil pdf. Ẹsẹ 17–20. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers