Al-Anfal · 58/75
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Anfal
وَإِمَّا تَخَافَنَّ مِن قَوْمٍ خِيَانَةً فَانبِذْ إِلَيْهِمْ عَلَىٰ سَوَاءٍ ۚ إِنَّ اللَّهَ لَا يُحِبُّ الْخَائِنِينَ ٥٨
Transliteration
Wa immaa takhaafana min qawmin khiyaanatan fambiz ilaihim `alaa sawaaa`; innal laaha laayuhibbul khaaa`ineen
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
tabi ti o ba si n paya iwa ijanba lati odo ijo kan, ju adehun won sile fun won ki e di jo mo pe ko si adehun kan mo laaarin eyin mejeeji. Dajudaju Allahu ko nifee awon onijanba
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 56-60 — Al-Anfal
56الَّذِينَ عَاهَدتَّ مِنْهُمْ ثُمَّ يَنقُضُونَ عَهْدَهُمْ فِي كُلِّ مَرَّةٍ وَهُمْ لَا يَتَّقُونَ
Awon ti o ba se adehun ninu won, leyin naa ti won n tu adehun won ni gbogbo igba, ti won ko si beru (Allahu)
57فَإِمَّا تَثْقَفَنَّهُمْ فِي الْحَرْبِ فَشَرِّدْ بِهِم مَّنْ خَلْفَهُمْ لَعَلَّهُمْ يَذَّكَّرُونَ
yala ti owo yin ba ba won loju ogun, (e pa won) ki e si (fi ogun) tu awon omoleyin won ka nitori ki won le lo iranti
58وَإِمَّا تَخَافَنَّ مِن قَوْمٍ خِيَانَةً فَانبِذْ إِلَيْهِمْ عَلَىٰ سَوَاءٍ ۚ إِنَّ اللَّهَ لَا يُحِبُّ الْخَائِنِينَ
tabi ti o ba si n paya iwa ijanba lati odo ijo kan, ju adehun won sile fun won ki e di jo mo pe ko si adehun kan mo laaarin eyin mejeeji. Dajudaju Allahu ko nifee awon onijanba
59وَلَا يَحْسَبَنَّ الَّذِينَ كَفَرُوا سَبَقُوا ۚ إِنَّهُمْ لَا يُعْجِزُونَ
Ki awon t’o sai gbagbo ma se lero pe awon ti gbawaju. Dajudaju won ko le mori bo (ninu iya)
60وَأَعِدُّوا لَهُم مَّا اسْتَطَعْتُم مِّن قُوَّةٍ وَمِن رِّبَاطِ الْخَيْلِ تُرْهِبُونَ بِهِ عَدُوَّ اللَّهِ وَعَدُوَّكُمْ وَآخَرِينَ مِن دُونِهِمْ لَا تَعْلَمُونَهُمُ اللَّهُ يَعْلَمُهُمْ ۚ وَمَا تُنفِقُوا مِن شَيْءٍ فِي سَبِيلِ اللَّهِ يُوَفَّ إِلَيْكُمْ وَأَنتُمْ لَا تُظْلَمُونَ
E pese sile de won nnkan ija ti agbara yin ka ninu nnkan amusagbara ati awon esin ori iso, ti eyin yoo fi maa deru ba ota Allahu ati ota yin pelu awon miiran yato si won, ti eyin ko mo won – Allahu si mo won. – Ohunkohun ti e ba na loju ona (esin) Allahu, A oo san an pada fun yin ni kikun; A o si nii se abosi fun yin
Al-AnfalAtokọ Kurani
75Ẹsẹ
MedinanRevelation
58Ẹsẹ
Itumọ — Al-Anfal 58
Surah Al-Anfal Ẹsẹ 58 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : tabi ti o ba si n paya iwa ijanba lati…Surah Ẹsẹ 58/75 — Al-Anfal الأنفال (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Anfal Gbọ, Al-Anfal Itumọ, Al-Anfal mp3, Al-Anfal pdf. Ẹsẹ 56–60. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








