At-Tawbah · 50/129
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah At-Tawbah
إِن تُصِبْكَ حَسَنَةٌ تَسُؤْهُمْ ۖ وَإِن تُصِبْكَ مُصِيبَةٌ يَقُولُوا قَدْ أَخَذْنَا أَمْرَنَا مِن قَبْلُ وَيَتَوَلَّوا وَّهُمْ فَرِحُونَ ۝٥٠
in tusibka hasanatun tasu`hum; wa in tusibka museebatuny yaqooloo qad akhaznaaa amranaa min qablu wa yatawallaw wa hum farihoon
📖 Ni Yorùbá
Ti daadaa ba sele si o, o maa ba won ninu je. Ti aida ba si sele si o, won a wi pe: “A kuku ti gba ase tiwa siwaju (lati jokoo sile.)” Won a peyin da; won yo si maa dunnu

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 48-52 — Surah At-Tawbah

48لَقَدِ ابْتَغَوُا الْفِتْنَةَ مِن قَبْلُ وَقَلَّبُوا لَكَ الْأُمُورَ حَتَّىٰ جَاءَ الْحَقُّ وَظَهَرَ أَمْرُ اللَّهِ وَهُمْ كَارِهُونَ
Won kuku ti da iyonu sile teletele. Won si doju awon oro ru fun o titi ododo fi de, ti ase Allahu si foju han kedere; emi won si ko o
49وَمِنْهُم مَّن يَقُولُ ائْذَن لِّي وَلَا تَفْتِنِّي ۚ أَلَا فِي الْفِتْنَةِ سَقَطُوا ۗ وَإِنَّ جَهَنَّمَ لَمُحِيطَةٌ بِالْكَافِرِينَ
O wa ninu won, eni ti n wi pe: “Yonda fun mi (ki ng jokoo sile); ma se ko mi sinu adanwo.” Inu adanwo (sisa fogun esin) ma ni won ti subu si yii. Dajudaju ina Jahanamo yo si kuku yi awon alaigbagbo po
50إِن تُصِبْكَ حَسَنَةٌ تَسُؤْهُمْ ۖ وَإِن تُصِبْكَ مُصِيبَةٌ يَقُولُوا قَدْ أَخَذْنَا أَمْرَنَا مِن قَبْلُ وَيَتَوَلَّوا وَّهُمْ فَرِحُونَ
Ti daadaa ba sele si o, o maa ba won ninu je. Ti aida ba si sele si o, won a wi pe: “A kuku ti gba ase tiwa siwaju (lati jokoo sile.)” Won a peyin da; won yo si maa dunnu
51قُل لَّن يُصِيبَنَا إِلَّا مَا كَتَبَ اللَّهُ لَنَا هُوَ مَوْلَانَا ۚ وَعَلَى اللَّهِ فَلْيَتَوَكَّلِ الْمُؤْمِنُونَ
So pe: “Ko si ohun kan t’o maa sele si wa ayafi ohun ti Allahu ko mo wa. Oun ni Alaabo wa.” Allahu si ni ki awon onigbagbo ododo gbarale
52قُلْ هَلْ تَرَبَّصُونَ بِنَا إِلَّا إِحْدَى الْحُسْنَيَيْنِ ۖ وَنَحْنُ نَتَرَبَّصُ بِكُمْ أَن يُصِيبَكُمُ اللَّهُ بِعَذَابٍ مِّنْ عِندِهِ أَوْ بِأَيْدِينَا ۖ فَتَرَبَّصُوا إِنَّا مَعَكُم مُّتَرَبِّصُونَ
So pe: "Se e n reti kini kan pelu wa ni bi ko se okan ninu daadaa meji (iku ogun tabi isegun)? Awa naa n reti pelu yin pe ki Allahu mu iya kan wa ba yin lati odo Re tabi lati owo wa. Nitori naa, e maa reti, dajudaju awa naa wa pelu yin ti a n reti
At-TawbahAtokọ Kurani
129Ẹsẹ
MedinanRevelation
50Ẹsẹ

Itumọ — At-Tawbah 50

Surah At-Tawbah Ẹsẹ 50 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ti daadaa ba sele si o, o maa ba won…

Surah Ẹsẹ 50/129 — Surah At-Tawbah التوبة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah At-Tawbah Gbọ, Surah At-Tawbah Itumọ, Surah At-Tawbah mp3, Surah At-Tawbah pdf. Ẹsẹ 48–52. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, September 8, 2026

Don't forget us in your sincere prayers