Surah At-Tariq pdf — Gbà (Yorùbá)
Surah At-Tariq pdf Yorùbá — Gbà Surah At-Tariq Itumọ. Surah At-Tariq (Meccan) 17 Ẹsẹ.
Related
- Surah At-Tariq ItumọYorùbá
- Surah At-Tariq mp3Gbọ
- Quran Index Yorùbá114
More Surah PDF
Surah At-Tariq

ﭑﭒﭓ
86:1
(Allahu) bura pelu sanmo ati Toriƙ
ﭔﭕﭖﭗﭘ
86:2
Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je Toriƙ
ﭙﭚﭛ
86:3
Irawo ti imole re n tan roro (ni ale ni)
ﭜﭝﭞﭟﭠﭡﭢ
86:4
Ko si emi kan afi ki eso kan wa fun un (ninu awon molaika)
ﭣﭤﭥﭦﭧ
86:5
Nitori naa, ki eniyan woye si ohun ti A fi seda re
ﭨﭩﭪﭫﭬ
86:6
Won seda re lati inu omi t’o n tu jade kookoo
ﭭﭮﭯﭰﭱﭲ
86:7
O n jade lati aarin ibadi okunrin ati awon efonha igba-aya obinrin
ﭳﭴﭵﭶﭷ
86:8
Dajudaju Allahu ni Alagbara lori idapada re
ﭸﭹﭺﭻ
86:9
ni ojo ti won maa se ayewo awon (ise) asepamo
ﭼﭽﭾﭿﮀﮁﮂ
86:10
Nigba naa, ko nii si agbara tabi alaranse kan fun un
ﮃﮄﮅﮆ
86:11
Allahu bura pelu sanmo t’o n ro ojo ni odoodun
ﮇﮈﮉﮊ
86:12
O tun bura pelu ile t’o n san kankan (fun hihujade eso)
ﮋﮌﮍﮎ
86:13
Dajudaju al-Ƙur’an ni oro-ipinya (laaarin ododo ati iro)
ﮏﮐﮑﮒ
86:14
Ki i si se awada
ﮓﮔﮕﮖ
86:15
Dajudaju won n dete gan-an
ﮗﮘﮙ
86:16
Emi naa si n dete gan-an
ﮚﮛﮜﮝﮞ
86:17
Nitori naa, lora fun awon alaigbagbo. Lo won lara se fun igba die
Al-Kur'an
Wednesday, September 9, 2026
Don't forget us in your sincere prayers







