PDF —
22 Ẹsẹ Meccan PDF
Built right in your browser — download starts automatically

Surah Al-Buruj pdf — Gbà (Yorùbá)

Surah Al-Buruj pdf Yorùbá — Gbà Surah Al-Buruj Itumọ. Surah Al-Buruj (Meccan) 22 Ẹsẹ.



22 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﭛﭜﭝﭞ
85:1 (Allahu) bura pelu sanmo ti awon ibuso (oorun, osupa ati awon irawo) wa ninu re
ﭟﭠﭡ
85:2 O tun bura pelu ojo ti won se ni adehun
ﭢﭣﭤ
85:3 O tun bura pelu olujerii ati ohun t’o jerii si
ﭥﭦﭧﭨ
85:4 A sebi le awon t’o gbe koto (ina)
ﭩﭪﭫﭬ
85:5 (iyen) ina ti won n fi igi ko (ninu koto)
ﭭﭮﭯﭰﭱ
85:6 (Ranti) nigba ti won jokoo si itosi re
ﭲﭳﭴﭵﭶﭷﭸ
85:7 Won si n wo ohun ti won n se fun awon onigbagbo ododo
ﭹﭺﭻﭼﭽﭾﭿﮀﮁﮂ
85:8 Ko si si kini kan ti won tori re je won niya bi ko se pe won ni igbagbo ododo ninu Allahu, Alagbara, Olope
ﮃﮄﮅﮆﮇﮈﮉﮊﮋﮌﮍﮎ
85:9 Eni ti O ni ijoba awon sanmo ati ile. Allahu si ni Elerii lori gbogbo nnkan
ﮏﮐﮑﮒﮓﮔﮕﮖﮗﮘﮙﮚﮛﮜﮝ
85:10 Dajudaju awon t’o fi inira kan awon onigbagbo ododo lokunrin ati awon onigbagbo ododo lobinrin, leyin naa ti won ko ronu piwada, iya ina Jahanamo n be fun won. Iya ina t’o n jo si wa fun won
ﮞﮟﮠﮡﮢﮣﮤﮥﮦﮧﮨﮩﮪﮫﮬﮭ
85:11 Dajudaju awon t’o gbagbo ni ododo, ti won si se awon ise rere, tiwon ni awon Ogba Idera kan, ti awon odo n san ni isale re. Iyen si ni erenje nla
ﮮﮯﮰﮱﯓ
85:12 Dajudaju igbamu ti Oluwa re ma le
ﯔﯕﯖﯗﯘ
85:13 Dajudaju Oun ni O pile (eda), O si maa da (eda) pada (fun ajinde)
ﯙﯚﯛﯜ
85:14 Oun ni Alaforijin, Ololufe (eda)
ﯝﯞﯟﯠ
85:15 Oun l’O ni Ite-ola, Eni-owo julo
ﯡﯢﯣﯤ
85:16 Oluse-ohun-t’O-ba-fe
ﯥﯦﯧﯨﯩ
85:17 Sebi iro awon omo ogun ti de odo re
ﯪﯫﯬ
85:18 (omo ogun) Fir‘aon ati (ijo) Thamud
ﯭﯮﯯﯰﯱﯲ
85:19 Sibesibe awon t’o sai gbagbo si n pe ododo niro
ﯳﯴﯵﯶﯷ
85:20 Allahu si yi won ka leyin won
ﯸﯹﯺﯻﯼ
85:21 Amo sa, ohun (ti A fi ranse si o ni) al-Ƙur’an alapon-onle
ﯽﯾﯿﰀ
85:22 ti o wa ninu walaa ti A n so

Al-Kur'an


Wednesday, September 9, 2026

Don't forget us in your sincere prayers