Al-Baqarah · 199/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Baqarah
ثُمَّ أَفِيضُوا مِنْ حَيْثُ أَفَاضَ النَّاسُ وَاسْتَغْفِرُوا اللَّهَ ۚ إِنَّ اللَّهَ غَفُورٌ رَّحِيمٌ ۝١٩٩
Summa afeedoo min haisu afaadan naasu wastagh firullaah; innnal laaha Ghafoo rur-Raheem
📖 Ni Yorùbá
Leyin naa, e da lo si ibi ti awon eniyan ba da lo (ninu ise Hajj), ki e si toro aforijin Allahu. Dajudaju, Allahu ni Alaforijin, Asake-orun
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 197-201 — Al-Baqarah

197الْحَجُّ أَشْهُرٌ مَّعْلُومَاتٌ ۚ فَمَن فَرَضَ فِيهِنَّ الْحَجَّ فَلَا رَفَثَ وَلَا فُسُوقَ وَلَا جِدَالَ فِي الْحَجِّ ۗ وَمَا تَفْعَلُوا مِنْ خَيْرٍ يَعْلَمْهُ اللَّهُ ۗ وَتَزَوَّدُوا فَإِنَّ خَيْرَ الزَّادِ التَّقْوَىٰ ۚ وَاتَّقُونِ يَا أُولِي الْأَلْبَابِ
Hajj sise (wa) ninu awon osu ti A ti mo. Nitori naa, enikeni ti o ba se e ni oran-anyan lori ara re lati se Hajj ninu awon osu naa, ko gbodo si oorun ife, ese dida ati ariyanjiyan ninu ise Hajj. Ohunkohun ti e ba se ni rere, Allahu mo on. E mu ese irin-ajo lowo. Dajudaju ese irin-ajo t’o loore julo ni isora (nibi ese elomiiran ati agbe sise l’asiko ise Hajj). E beru Mi, eyin onilaakaye
198لَيْسَ عَلَيْكُمْ جُنَاحٌ أَن تَبْتَغُوا فَضْلًا مِّن رَّبِّكُمْ ۚ فَإِذَا أَفَضْتُم مِّنْ عَرَفَاتٍ فَاذْكُرُوا اللَّهَ عِندَ الْمَشْعَرِ الْحَرَامِ ۖ وَاذْكُرُوهُ كَمَا هَدَاكُمْ وَإِن كُنتُم مِّن قَبْلِهِ لَمِنَ الضَّالِّينَ
Ko si ibawi fun yin (nibi owo sise l’asiko ise hajj) pe ki e wa oore kan lati odo Oluwa yin. Nitori naa, ti e ba n dari bo lati ‘Arafah, e se iranti Allahu ni aye alapon-onle (Muzdalifah). E se iranti Re gege bi O se fi ona mo yin, bi o tile je pe teletele e wa ninu awon olusina
199ثُمَّ أَفِيضُوا مِنْ حَيْثُ أَفَاضَ النَّاسُ وَاسْتَغْفِرُوا اللَّهَ ۚ إِنَّ اللَّهَ غَفُورٌ رَّحِيمٌ
Leyin naa, e da lo si ibi ti awon eniyan ba da lo (ninu ise Hajj), ki e si toro aforijin Allahu. Dajudaju, Allahu ni Alaforijin, Asake-orun
200فَإِذَا قَضَيْتُم مَّنَاسِكَكُمْ فَاذْكُرُوا اللَّهَ كَذِكْرِكُمْ آبَاءَكُمْ أَوْ أَشَدَّ ذِكْرًا ۗ فَمِنَ النَّاسِ مَن يَقُولُ رَبَّنَا آتِنَا فِي الدُّنْيَا وَمَا لَهُ فِي الْآخِرَةِ مِنْ خَلَاقٍ
Nigba ti e ba pari ijosin (Hajj) yin, e seranti Allahu gege bi e se n seranti awon baba nla yin. Tabi ki iranti naa lagbara ju bee lo. Nitori naa, o n be ninu awon eniyan, eni t’o n wi pe: “Oluwa wa, fun wa ni oore aye.” Ko si nii si ipin oore kan fun un ni orun
201وَمِنْهُم مَّن يَقُولُ رَبَّنَا آتِنَا فِي الدُّنْيَا حَسَنَةً وَفِي الْآخِرَةِ حَسَنَةً وَقِنَا عَذَابَ النَّارِ
O si n be ninu won, eni t’o n so pe: "Oluwa wa, fun wa ni oore ni aye ati oore ni orun, ki O si so wa nibi iya Ina
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
199Ẹsẹ

Itumọ — Al-Baqarah 199

Surah Al-Baqarah Ẹsẹ 199 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Leyin naa, e da lo si ibi ti awon eniyan…

Surah Ẹsẹ 199/286 — Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Baqarah Gbọ, Al-Baqarah Itumọ, Al-Baqarah mp3, Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 197–201. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers