Al-Baqarah · 200/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Baqarah
فَإِذَا قَضَيْتُم مَّنَاسِكَكُمْ فَاذْكُرُوا اللَّهَ كَذِكْرِكُمْ آبَاءَكُمْ أَوْ أَشَدَّ ذِكْرًا ۗ فَمِنَ النَّاسِ مَن يَقُولُ رَبَّنَا آتِنَا فِي الدُّنْيَا وَمَا لَهُ فِي الْآخِرَةِ مِنْ خَلَاقٍ ٢٠٠
Transliteration
Fa-izan qadaitum manaa sikakum fazkurul laaha kazikrikum aabaaa`akum aw ashadda zikraa; faminannaasi mai yaqoolu Rabbanaaa aatinaa fiddunyaa wa maa lahoo fil Aakhirati min khalaaq
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Nigba ti e ba pari ijosin (Hajj) yin, e seranti Allahu gege bi e se n seranti awon baba nla yin. Tabi ki iranti naa lagbara ju bee lo. Nitori naa, o n be ninu awon eniyan, eni t’o n wi pe: “Oluwa wa, fun wa ni oore aye.” Ko si nii si ipin oore kan fun un ni orun
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 198-202 — Al-Baqarah
198لَيْسَ عَلَيْكُمْ جُنَاحٌ أَن تَبْتَغُوا فَضْلًا مِّن رَّبِّكُمْ ۚ فَإِذَا أَفَضْتُم مِّنْ عَرَفَاتٍ فَاذْكُرُوا اللَّهَ عِندَ الْمَشْعَرِ الْحَرَامِ ۖ وَاذْكُرُوهُ كَمَا هَدَاكُمْ وَإِن كُنتُم مِّن قَبْلِهِ لَمِنَ الضَّالِّينَ
Ko si ibawi fun yin (nibi owo sise l’asiko ise hajj) pe ki e wa oore kan lati odo Oluwa yin. Nitori naa, ti e ba n dari bo lati ‘Arafah, e se iranti Allahu ni aye alapon-onle (Muzdalifah). E se iranti Re gege bi O se fi ona mo yin, bi o tile je pe teletele e wa ninu awon olusina
199ثُمَّ أَفِيضُوا مِنْ حَيْثُ أَفَاضَ النَّاسُ وَاسْتَغْفِرُوا اللَّهَ ۚ إِنَّ اللَّهَ غَفُورٌ رَّحِيمٌ
Leyin naa, e da lo si ibi ti awon eniyan ba da lo (ninu ise Hajj), ki e si toro aforijin Allahu. Dajudaju, Allahu ni Alaforijin, Asake-orun
200فَإِذَا قَضَيْتُم مَّنَاسِكَكُمْ فَاذْكُرُوا اللَّهَ كَذِكْرِكُمْ آبَاءَكُمْ أَوْ أَشَدَّ ذِكْرًا ۗ فَمِنَ النَّاسِ مَن يَقُولُ رَبَّنَا آتِنَا فِي الدُّنْيَا وَمَا لَهُ فِي الْآخِرَةِ مِنْ خَلَاقٍ
Nigba ti e ba pari ijosin (Hajj) yin, e seranti Allahu gege bi e se n seranti awon baba nla yin. Tabi ki iranti naa lagbara ju bee lo. Nitori naa, o n be ninu awon eniyan, eni t’o n wi pe: “Oluwa wa, fun wa ni oore aye.” Ko si nii si ipin oore kan fun un ni orun
201وَمِنْهُم مَّن يَقُولُ رَبَّنَا آتِنَا فِي الدُّنْيَا حَسَنَةً وَفِي الْآخِرَةِ حَسَنَةً وَقِنَا عَذَابَ النَّارِ
O si n be ninu won, eni t’o n so pe: "Oluwa wa, fun wa ni oore ni aye ati oore ni orun, ki O si so wa nibi iya Ina
202أُولَٰئِكَ لَهُمْ نَصِيبٌ مِّمَّا كَسَبُوا ۚ وَاللَّهُ سَرِيعُ الْحِسَابِ
Awon wonyen, tiwon ni ipin oore nipa ohun ti won se nise. Allahu si ni Oluyara nibi isiro-ise
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
200Ẹsẹ
Itumọ — Al-Baqarah 200
Surah Al-Baqarah Ẹsẹ 200 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Nigba ti e ba pari ijosin (Hajj) yin, e seranti…Surah Ẹsẹ 200/286 — Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Baqarah Gbọ, Al-Baqarah Itumọ, Al-Baqarah mp3, Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 198–202. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








