Al-Baqarah · 242/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Baqarah
كَذَٰلِكَ يُبَيِّنُ اللَّهُ لَكُمْ آيَاتِهِ لَعَلَّكُمْ تَعْقِلُونَ ۝٢٤٢
Kazaalika yubaiyinul laahu lakum aayaatihee la`allakum ta`qiloon
📖 Ni Yorùbá
Bayen ni Allahu se n salaye awon ayah Re fun yin, nitori ki e le se laakaye
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 240-244 — Al-Baqarah

240وَالَّذِينَ يُتَوَفَّوْنَ مِنكُمْ وَيَذَرُونَ أَزْوَاجًا وَصِيَّةً لِّأَزْوَاجِهِم مَّتَاعًا إِلَى الْحَوْلِ غَيْرَ إِخْرَاجٍ ۚ فَإِنْ خَرَجْنَ فَلَا جُنَاحَ عَلَيْكُمْ فِي مَا فَعَلْنَ فِي أَنفُسِهِنَّ مِن مَّعْرُوفٍ ۗ وَاللَّهُ عَزِيزٌ حَكِيمٌ
Awon ti won ku ninu yin, ti won si fi awon iyawo saye lo, ki won se asoole ije-imu odun kan fun awon iyawo won, lai si nii le won jade kuro ninu ile won. Ti won ba si jade (funra won leyin ijade opo), ko si ese fun yin nipa ohun ti won ba fi’ra won se ni daadaa (lati ni oko miiran). Allahu ni Alagbara, Ologbon
241وَلِلْمُطَلَّقَاتِ مَتَاعٌ بِالْمَعْرُوفِ ۖ حَقًّا عَلَى الْمُتَّقِينَ
Nnkan igbadun ni ona t’o dara tun maa wa fun awon obinrin ti won kosile. Ojuse l’o je fun awon oluberu Allahu
242كَذَٰلِكَ يُبَيِّنُ اللَّهُ لَكُمْ آيَاتِهِ لَعَلَّكُمْ تَعْقِلُونَ
Bayen ni Allahu se n salaye awon ayah Re fun yin, nitori ki e le se laakaye
243۞ أَلَمْ تَرَ إِلَى الَّذِينَ خَرَجُوا مِن دِيَارِهِمْ وَهُمْ أُلُوفٌ حَذَرَ الْمَوْتِ فَقَالَ لَهُمُ اللَّهُ مُوتُوا ثُمَّ أَحْيَاهُمْ ۚ إِنَّ اللَّهَ لَذُو فَضْلٍ عَلَى النَّاسِ وَلَٰكِنَّ أَكْثَرَ النَّاسِ لَا يَشْكُرُونَ
Se o o ri awon t’o jade lati inu ile won legbeegberun nitori iberu iku! Allahu si so fun won pe: “E ku.” Leyin naa, O so won di alaaye. Dajudaju Allahu ni Oloore-ajulo lori awon eniyan, sugbon opolopo eniyan ko dupe (fun Un)
244وَقَاتِلُوا فِي سَبِيلِ اللَّهِ وَاعْلَمُوا أَنَّ اللَّهَ سَمِيعٌ عَلِيمٌ
E jagun fun aabo esin Allahu, ki e si mo pe dajudaju Allahu ni Olugbo, Onimo
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
242Ẹsẹ

Itumọ — Al-Baqarah 242

Surah Al-Baqarah Ẹsẹ 242 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Bayen ni Allahu se n salaye awon ayah Re fun…

Surah Ẹsẹ 242/286 — Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Baqarah Gbọ, Al-Baqarah Itumọ, Al-Baqarah mp3, Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 240–244. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers