Al-Baqarah · 243/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Baqarah
۞ أَلَمۡ تَرَ إِلَى ٱلَّذِينَ خَرَجُواْ مِن دِيَٰرِهِمۡ وَهُمۡ أُلُوفٌ حَذَرَ ٱلۡمَوۡتِ فَقَالَ لَهُمُ ٱللَّهُ مُوتُواْ ثُمَّ أَحۡيَٰهُمۡۚ إِنَّ ٱللَّهَ لَذُو فَضۡلٍ عَلَى ٱلنَّاسِ وَلَٰكِنَّ أَكۡثَرَ ٱلنَّاسِ لَا يَشۡكُرُونَ  ۝٢٤٣
Alam tara ilal lazeena kharajoo min diyaarihim wa hum uloofun hazaral mawti faqaaala lahumul laahu mootoo summa ahyaahum; innal laaha lazoo fadlin `alannaasi wa laakinna aksarannaasi laa yashkuroon
📖 Ni Yorùbá
Se o o ri awon t’o jade lati inu ile won legbeegberun nitori iberu iku! Allahu si so fun won pe: “E ku.” Leyin naa, O so won di alaaye. Dajudaju Allahu ni Oloore-ajulo lori awon eniyan, sugbon opolopo eniyan ko dupe (fun Un)
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 241-245 — Al-Baqarah

241وَلِلۡمُطَلَّقَٰتِ مَتَٰعُۢ بِٱلۡمَعۡرُوفِۖ حَقًّا عَلَى ٱلۡمُتَّقِينَ 
Nnkan igbadun ni ona t’o dara tun maa wa fun awon obinrin ti won kosile. Ojuse l’o je fun awon oluberu Allahu
242كَذَٰلِكَ يُبَيِّنُ ٱللَّهُ لَكُمۡ ءَايَٰتِهِۦ لَعَلَّكُمۡ تَعۡقِلُونَ 
Bayen ni Allahu se n salaye awon ayah Re fun yin, nitori ki e le se laakaye
243۞ أَلَمۡ تَرَ إِلَى ٱلَّذِينَ خَرَجُواْ مِن دِيَٰرِهِمۡ وَهُمۡ أُلُوفٌ حَذَرَ ٱلۡمَوۡتِ فَقَالَ لَهُمُ ٱللَّهُ مُوتُواْ ثُمَّ أَحۡيَٰهُمۡۚ إِنَّ ٱللَّهَ لَذُو فَضۡلٍ عَلَى ٱلنَّاسِ وَلَٰكِنَّ أَكۡثَرَ ٱلنَّاسِ لَا يَشۡكُرُونَ 
Se o o ri awon t’o jade lati inu ile won legbeegberun nitori iberu iku! Allahu si so fun won pe: “E ku.” Leyin naa, O so won di alaaye. Dajudaju Allahu ni Oloore-ajulo lori awon eniyan, sugbon opolopo eniyan ko dupe (fun Un)
244وَقَٰتِلُواْ فِي سَبِيلِ ٱللَّهِ وَٱعۡلَمُوٓاْ أَنَّ ٱللَّهَ سَمِيعٌ عَلِيمٌ 
E jagun fun aabo esin Allahu, ki e si mo pe dajudaju Allahu ni Olugbo, Onimo
245مَّن ذَا ٱلَّذِي يُقۡرِضُ ٱللَّهَ قَرۡضًا حَسَنًا فَيُضَٰعِفَهُۥ لَهُۥٓ أَضۡعَافًا كَثِيرَةًۚ وَٱللَّهُ يَقۡبِضُ وَيَبۡصُۜطُ وَإِلَيۡهِ تُرۡجَعُونَ 
Ta ni eni ti o maa ya Allahu ni dukia t’o dara, ki Allahu si se adipele (esan) fun un ni adipele pupo? Allahu n ka oro nile, O si n te e sile. Odo Re si ni won yoo da yin pada si
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
243Ẹsẹ

Itumọ — Al-Baqarah 243

Surah Ẹsẹ 243/286 — Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Baqarah Gbọ, Al-Baqarah Itumọ, Al-Baqarah mp3, Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 241–245. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers