Al-Baqarah · 94/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Baqarah
قُلْ إِن كَانَتْ لَكُمُ الدَّارُ الْآخِرَةُ عِندَ اللَّهِ خَالِصَةً مِّن دُونِ النَّاسِ فَتَمَنَّوُا الْمَوْتَ إِن كُنتُمْ صَادِقِينَ ۝٩٤
Qul in kaanat lakumud Daarul Aakhiratu `indal laahi khaalisatam min doonin naasi fatamannawul mawta in kuntum saadiqeen
📖 Ni Yorùbá
So pe: “Ti o ba je pe tiyin nikan ni Ile Ikeyin ti n be ni odo Allahu, ti ko si nii je ti awon eniyan (miiran), e toro iku, ti e ba je olododo

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 92-96 — Surah Al-Baqarah

92۞ وَلَقَدْ جَاءَكُم مُّوسَىٰ بِالْبَيِّنَاتِ ثُمَّ اتَّخَذْتُمُ الْعِجْلَ مِن بَعْدِهِ وَأَنتُمْ ظَالِمُونَ
Ati pe dajudaju (Anabi) Musa ti mu awon eri t’o yanju wa ba yin. Leyin naa, e tun bo oborogidi omo maalu leyin re. Alabosi si ni yin.”
93وَإِذْ أَخَذْنَا مِيثَاقَكُمْ وَرَفَعْنَا فَوْقَكُمُ الطُّورَ خُذُوا مَا آتَيْنَاكُم بِقُوَّةٍ وَاسْمَعُوا ۖ قَالُوا سَمِعْنَا وَعَصَيْنَا وَأُشْرِبُوا فِي قُلُوبِهِمُ الْعِجْلَ بِكُفْرِهِمْ ۚ قُلْ بِئْسَمَا يَأْمُرُكُم بِهِ إِيمَانُكُمْ إِن كُنتُم مُّؤْمِنِينَ
(E ranti) nigba ti A gba adehun lowo yin, A si gbe apata s’oke ori yin, (A so pe:) "E gba ohun ti A fun yin mu daradara. Ki e si teti gboro." Won wi pe: "A gbo (ase), a si yapa (ase)." Won ti ko ife bibo oborogidi omo maalu sinu okan won nipase aigbagbo won. So pe: "Aburu ni ohun ti igbagbo (iborisa) yin n pa yin lase re, ti e ba je onigbagbo ododo
94قُلْ إِن كَانَتْ لَكُمُ الدَّارُ الْآخِرَةُ عِندَ اللَّهِ خَالِصَةً مِّن دُونِ النَّاسِ فَتَمَنَّوُا الْمَوْتَ إِن كُنتُمْ صَادِقِينَ
So pe: “Ti o ba je pe tiyin nikan ni Ile Ikeyin ti n be ni odo Allahu, ti ko si nii je ti awon eniyan (miiran), e toro iku, ti e ba je olododo
95وَلَن يَتَمَنَّوْهُ أَبَدًا بِمَا قَدَّمَتْ أَيْدِيهِمْ ۗ وَاللَّهُ عَلِيمٌ بِالظَّالِمِينَ
Won ko nii toro iku laelae nitori ohun ti owo won ti siwaju. Allahu si ni Onimo nipa awon alabosi
96وَلَتَجِدَنَّهُمْ أَحْرَصَ النَّاسِ عَلَىٰ حَيَاةٍ وَمِنَ الَّذِينَ أَشْرَكُوا ۚ يَوَدُّ أَحَدُهُمْ لَوْ يُعَمَّرُ أَلْفَ سَنَةٍ وَمَا هُوَ بِمُزَحْزِحِهِ مِنَ الْعَذَابِ أَن يُعَمَّرَ ۗ وَاللَّهُ بَصِيرٌ بِمَا يَعْمَلُونَ
Dajudaju o maa ri won pe awon ni eniyan t’o l’oju kokoro julo nipa isemi aye, (won tun l’oju kokoro ju) awon osebo lo. Ikookan won n fe pe ti A ba le fun oun ni egberun odun lo laye. Bee si ni, ki i se ohun ti o maa la a ninu iya ni pe ki A fun un ni isemi gigun lo. Allahu si ni Oluriran nipa ohun ti won n se nise
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
94Ẹsẹ

Itumọ — Al-Baqarah 94

Surah Al-Baqarah Ẹsẹ 94 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : So pe: “Ti o ba je pe tiyin nikan ni…

Surah Ẹsẹ 94/286 — Surah Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Baqarah Gbọ, Surah Al-Baqarah Itumọ, Surah Al-Baqarah mp3, Surah Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 92–96. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers