Aal-Imran · 43/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Aal-Imran
يَا مَرْيَمُ اقْنُتِي لِرَبِّكِ وَاسْجُدِي وَارْكَعِي مَعَ الرَّاكِعِينَ ۝٤٣
Yaa Maryamuq nutee li Rabbiki wasjudee warka`ee ma`ar raaki`een
📖 Ni Yorùbá
Moryam, tele ase Oluwa re. Fori kanle fun Un. Ki o si dawo te orunkun pelu awon oludawote-orunkun (lori irun)

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 41-45 — Surah Aal-Imran

41قَالَ رَبِّ اجْعَل لِّي آيَةً ۖ قَالَ آيَتُكَ أَلَّا تُكَلِّمَ النَّاسَ ثَلَاثَةَ أَيَّامٍ إِلَّا رَمْزًا ۗ وَاذْكُر رَّبَّكَ كَثِيرًا وَسَبِّحْ بِالْعَشِيِّ وَالْإِبْكَارِ
(Zakariyya) so pe: “Oluwa mi, fun mi ni ami kan.” (Molaika) so pe: "Ami re ni pe iwo ko nii le ba eniyan soro fun ojo meta ayafi titoka (si nnkan). Ranti Oluwa re lopolopo. Ki o si safomo (fun Un) ni asale ati ni owuro kutu
42وَإِذْ قَالَتِ الْمَلَائِكَةُ يَا مَرْيَمُ إِنَّ اللَّهَ اصْطَفَاكِ وَطَهَّرَكِ وَاصْطَفَاكِ عَلَىٰ نِسَاءِ الْعَالَمِينَ
(E ranti) nigba ti awon molaika so pe: “Moryam, dajudaju Allahu sa o lesa. O fo o mo. O si sa o lesa lori awon obinrin aye (asiko tire)
43يَا مَرْيَمُ اقْنُتِي لِرَبِّكِ وَاسْجُدِي وَارْكَعِي مَعَ الرَّاكِعِينَ
Moryam, tele ase Oluwa re. Fori kanle fun Un. Ki o si dawo te orunkun pelu awon oludawote-orunkun (lori irun)
44ذَٰلِكَ مِنْ أَنبَاءِ الْغَيْبِ نُوحِيهِ إِلَيْكَ ۚ وَمَا كُنتَ لَدَيْهِمْ إِذْ يُلْقُونَ أَقْلَامَهُمْ أَيُّهُمْ يَكْفُلُ مَرْيَمَ وَمَا كُنتَ لَدَيْهِمْ إِذْ يَخْتَصِمُونَ
Iyen wa ninu iro ikoko ti A n fi imisi re ranse si o. Iwo ko kuku si lodo won nigba ti won n ju gege won (lati mo) ta ni ninu won ni o maa gba Moryam wo. Iwo ko si si lodo won nigba ti won n se ifanfa (lori re)
45إِذْ قَالَتِ الْمَلَائِكَةُ يَا مَرْيَمُ إِنَّ اللَّهَ يُبَشِّرُكِ بِكَلِمَةٍ مِّنْهُ اسْمُهُ الْمَسِيحُ عِيسَى ابْنُ مَرْيَمَ وَجِيهًا فِي الدُّنْيَا وَالْآخِرَةِ وَمِنَ الْمُقَرَّبِينَ
(E ranti) nigba ti awon molaika so pe: "Moryam, dajudaju Allahu n fun o ni iro idunnu (nipa dida eda kan pelu) oro kan lati odo Re. Oruko re ni Mosih ‘Isa omo Moryam. Abiyi ni ni aye ati ni orun. O si wa lara alasun-unmo (Allahu). ninu ayah ti ali ‘Imron Allahu (subhanahu wa ta’ala) n so nipa bi awon mola’ikah se wa so asotele nipa bibi ‘Isa (’alaehi-ssolatu wa-ssalam). Awon molaika t’o wa so asotele naa ju eyo kan lo. Idi niyi ti “mola’ikah” fi je opo ninu ayah yen. Amo ninu ayah ti Moryam
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
43Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 43

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 43 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Moryam, tele ase Oluwa re. Fori kanle fun Un. Ki…

Surah Ẹsẹ 43/200 — Surah Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Aal-Imran Gbọ, Surah Aal-Imran Itumọ, Surah Aal-Imran mp3, Surah Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 41–45. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers