An-Nisa · 146/176
Itumọ Aṣẹ ohun — An-Nisa
إِلَّا الَّذِينَ تَابُوا وَأَصْلَحُوا وَاعْتَصَمُوا بِاللَّهِ وَأَخْلَصُوا دِينَهُمْ لِلَّهِ فَأُولَٰئِكَ مَعَ الْمُؤْمِنِينَ ۖ وَسَوْفَ يُؤْتِ اللَّهُ الْمُؤْمِنِينَ أَجْرًا عَظِيمًا ۝١٤٦
Illal lazeena taaboo wa aslahoo wa`tasamoo billaahi wa akhlasoo deenahum lillaahi faulaaa`ika ma`al mu`mineena wa sawfa yu`til laahul mu`mineena ajran `azeemaa
📖 Ni Yorùbá
Ayafi awon t’o ronu piwada, ti won se atunse, ti won duro sinsin ti Allahu, ti won si se afomo esin won fun Allahu. Nitori naa, awon wonyen maa wa pelu awon onigbagbo ododo. Laipe Allahu maa fun awon onigbagbo ododo ni esan nla
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 144-148 — An-Nisa

144يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا لَا تَتَّخِذُوا الْكَافِرِينَ أَوْلِيَاءَ مِن دُونِ الْمُؤْمِنِينَ ۚ أَتُرِيدُونَ أَن تَجْعَلُوا لِلَّهِ عَلَيْكُمْ سُلْطَانًا مُّبِينًا
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e ma se mu awon alaigbagbo ni ore ayo leyin awon onigbagbo ododo (egbe yin). Se e fe se nnkan ti Allahu yoo fi ni eri ponnbele lowo lati je yin niya ni
145إِنَّ الْمُنَافِقِينَ فِي الدَّرْكِ الْأَسْفَلِ مِنَ النَّارِ وَلَن تَجِدَ لَهُمْ نَصِيرًا
Dajudaju awon sobe-selu musulumi yoo wa ninu aja isale patapata ninu Ina. O o si nii ri alaranse kan fun won
146إِلَّا الَّذِينَ تَابُوا وَأَصْلَحُوا وَاعْتَصَمُوا بِاللَّهِ وَأَخْلَصُوا دِينَهُمْ لِلَّهِ فَأُولَٰئِكَ مَعَ الْمُؤْمِنِينَ ۖ وَسَوْفَ يُؤْتِ اللَّهُ الْمُؤْمِنِينَ أَجْرًا عَظِيمًا
Ayafi awon t’o ronu piwada, ti won se atunse, ti won duro sinsin ti Allahu, ti won si se afomo esin won fun Allahu. Nitori naa, awon wonyen maa wa pelu awon onigbagbo ododo. Laipe Allahu maa fun awon onigbagbo ododo ni esan nla
147مَّا يَفْعَلُ اللَّهُ بِعَذَابِكُمْ إِن شَكَرْتُمْ وَآمَنتُمْ ۚ وَكَانَ اللَّهُ شَاكِرًا عَلِيمًا
Ki ni Allahu maa fi iya yin se, ti e ba dupe, ti e si gbagbo ni ododo? Allahu si n je Olumoore, Onimo
148۞ لَّا يُحِبُّ اللَّهُ الْجَهْرَ بِالسُّوءِ مِنَ الْقَوْلِ إِلَّا مَن ظُلِمَ ۚ وَكَانَ اللَّهُ سَمِيعًا عَلِيمًا
Allahu ko nifee si ariwo epe sise (lati odo enikeni) ayafi eni ti won ba se abosi si. Allahu si n je Olugbo, Onimo
An-NisaAtokọ Kurani
176Ẹsẹ
MedinanRevelation
146Ẹsẹ

Itumọ — An-Nisa 146

Surah An-Nisa Ẹsẹ 146 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ayafi awon t’o ronu piwada, ti won se atunse, ti…

Surah Ẹsẹ 146/176 — An-Nisa النساء (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: An-Nisa Gbọ, An-Nisa Itumọ, An-Nisa mp3, An-Nisa pdf. Ẹsẹ 144–148. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers