Fussilat · 36/54
Itumọ Aṣẹ ohun — Fussilat
وَإِمَّا يَنزَغَنَّكَ مِنَ الشَّيْطَانِ نَزْغٌ فَاسْتَعِذْ بِاللَّهِ ۖ إِنَّهُ هُوَ السَّمِيعُ الْعَلِيمُ ٣٦
Transliteration
Wa immaa yanzaghannaka minash Shaitaani nazghun fasta`iz billaahi innahoo Huwas Samee`ul `Aleem
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Ati pe ti erokero kan lati odo Esu ba fe se o lori (kuro nibi iwa rere yii), sa di Allahu. Dajudaju Oun ni Olugbo, Onimo
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 34-38 — Fussilat
34وَلَا تَسْتَوِي الْحَسَنَةُ وَلَا السَّيِّئَةُ ۚ ادْفَعْ بِالَّتِي هِيَ أَحْسَنُ فَإِذَا الَّذِي بَيْنَكَ وَبَيْنَهُ عَدَاوَةٌ كَأَنَّهُ وَلِيٌّ حَمِيمٌ
Rere ati aburu ko dogba. Fi eyi ti o dara julo dena (aburu). Nigba naa ni eni ti ota wa laaarin iwo ati oun maa da bi ore alasun-unmo pekipeki
35وَمَا يُلَقَّاهَا إِلَّا الَّذِينَ صَبَرُوا وَمَا يُلَقَّاهَا إِلَّا ذُو حَظٍّ عَظِيمٍ
A o nii fun eni kan ni (iwa rere yii) afi awon t’o se suuru. A o nii fun eni kan se afi olori-ire nla
36وَإِمَّا يَنزَغَنَّكَ مِنَ الشَّيْطَانِ نَزْغٌ فَاسْتَعِذْ بِاللَّهِ ۖ إِنَّهُ هُوَ السَّمِيعُ الْعَلِيمُ
Ati pe ti erokero kan lati odo Esu ba fe se o lori (kuro nibi iwa rere yii), sa di Allahu. Dajudaju Oun ni Olugbo, Onimo
37وَمِنْ آيَاتِهِ اللَّيْلُ وَالنَّهَارُ وَالشَّمْسُ وَالْقَمَرُ ۚ لَا تَسْجُدُوا لِلشَّمْسِ وَلَا لِلْقَمَرِ وَاسْجُدُوا لِلَّهِ الَّذِي خَلَقَهُنَّ إِن كُنتُمْ إِيَّاهُ تَعْبُدُونَ
Ninu awon ami Re ni oru, osan, oorun ati osupa. E o gbodo fori kanle fun oorun ati osupa. E fori kanle fun Allahu, Eni ti O da won, ti eyin ba je eni t’o n josin fun Oun nikan soso
38فَإِنِ اسْتَكْبَرُوا فَالَّذِينَ عِندَ رَبِّكَ يُسَبِّحُونَ لَهُ بِاللَّيْلِ وَالنَّهَارِ وَهُمْ لَا يَسْأَمُونَ ۩
Ti won ba si segberaga, awon t’o wa ni odo Oluwa re, won n safomo fun Un ni ale ati ni osan; won ko si kagara
FussilatAtokọ Kurani
54Ẹsẹ
MeccanRevelation
36Ẹsẹ
Itumọ — Fussilat 36
Surah Fussilat Ẹsẹ 36 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ati pe ti erokero kan lati odo Esu ba fe…Surah Ẹsẹ 36/54 — Fussilat فصلت (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Fussilat Gbọ, Fussilat Itumọ, Fussilat mp3, Fussilat pdf. Ẹsẹ 34–38. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








