Ad-Dukhan · 3/59
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Ad-Dukhan
إِنَّا أَنزَلْنَاهُ فِي لَيْلَةٍ مُّبَارَكَةٍ ۚ إِنَّا كُنَّا مُنذِرِينَ ۝٣
Innaaa anzalnaahu fee lailatim mubaarakah; innaa kunnaa munzireen
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju Awa so o kale ninu oru ibukun. Dajudaju Awa n je Olukilo

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 1-5 — Surah Ad-Dukhan

1حم
Ha mim
2وَالْكِتَابِ الْمُبِينِ
(Allahu) bura pelu Tira t’o yanju oro eda
3إِنَّا أَنزَلْنَاهُ فِي لَيْلَةٍ مُّبَارَكَةٍ ۚ إِنَّا كُنَّا مُنذِرِينَ
Dajudaju Awa so o kale ninu oru ibukun. Dajudaju Awa n je Olukilo
4فِيهَا يُفْرَقُ كُلُّ أَمْرٍ حَكِيمٍ
Ninu oru naa ni won ti maa yanju gbogbo oro ti ko nii tase (lori eda)
5أَمْرًا مِّنْ عِندِنَا ۚ إِنَّا كُنَّا مُرْسِلِينَ
Ase kan ni lati odo Wa. Dajudaju Awa l’A n ran awon Ojise nise
Ad-DukhanAtokọ Kurani
59Ẹsẹ
MeccanRevelation
3Ẹsẹ

Itumọ — Ad-Dukhan 3

Surah Ad-Dukhan Ẹsẹ 3 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju Awa so o kale ninu oru ibukun. Dajudaju Awa…

Surah Ẹsẹ 3/59 — Surah Ad-Dukhan الدخان (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Ad-Dukhan Gbọ, Surah Ad-Dukhan Itumọ, Surah Ad-Dukhan mp3, Surah Ad-Dukhan pdf. Ẹsẹ 1–5. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers