Ar-Rahman · 16/78
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Ar-Rahman
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ ۝١٦
Fabi ayyi aalaaa`i Rabbikumaa tukazzibaan
📖 Ni Yorùbá
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 14-18 — Surah Ar-Rahman

14خَلَقَ الْإِنسَانَ مِن صَلْصَالٍ كَالْفَخَّارِ
(Allahu) seda eniyan lati ara amo gbigbe t’o n dun kokoko bi ikoko amo
15وَخَلَقَ الْجَانَّ مِن مَّارِجٍ مِّن نَّارٍ
O si seda alujannu lati ara ahon ina ti ko ni eefin
16فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
17رَبُّ الْمَشْرِقَيْنِ وَرَبُّ الْمَغْرِبَيْنِ
Oluwa ibuyo oorun mejeeji ati ibuwo oorun mejeeji
18فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
Ar-RahmanAtokọ Kurani
78Ẹsẹ
MedinanRevelation
16Ẹsẹ

Itumọ — Ar-Rahman 16

Surah Ar-Rahman Ẹsẹ 16 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati…

Surah Ẹsẹ 16/78 — Surah Ar-Rahman الرحمن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Ar-Rahman Gbọ, Surah Ar-Rahman Itumọ, Surah Ar-Rahman mp3, Surah Ar-Rahman pdf. Ẹsẹ 14–18. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers