Ar-Rahman · 15/78
Itumọ Aṣẹ ohun — Ar-Rahman
وَخَلَقَ الْجَانَّ مِن مَّارِجٍ مِّن نَّارٍ ۝١٥
Wa khalaqal jaaan mim maarijim min naar
📖 Ni Yorùbá
O si seda alujannu lati ara ahon ina ti ko ni eefin
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 13-17 — Ar-Rahman

13فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
14خَلَقَ الْإِنسَانَ مِن صَلْصَالٍ كَالْفَخَّارِ
(Allahu) seda eniyan lati ara amo gbigbe t’o n dun kokoko bi ikoko amo
15وَخَلَقَ الْجَانَّ مِن مَّارِجٍ مِّن نَّارٍ
O si seda alujannu lati ara ahon ina ti ko ni eefin
16فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
17رَبُّ الْمَشْرِقَيْنِ وَرَبُّ الْمَغْرِبَيْنِ
Oluwa ibuyo oorun mejeeji ati ibuwo oorun mejeeji
Ar-RahmanAtokọ Kurani
78Ẹsẹ
MedinanRevelation
15Ẹsẹ

Itumọ — Ar-Rahman 15

Surah Ar-Rahman Ẹsẹ 15 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : O si seda alujannu lati ara ahon ina ti ko…

Surah Ẹsẹ 15/78 — Ar-Rahman الرحمن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Ar-Rahman Gbọ, Ar-Rahman Itumọ, Ar-Rahman mp3, Ar-Rahman pdf. Ẹsẹ 13–17. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers