Ar-Rahman · 17/78
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Ar-Rahman
رَبُّ الْمَشْرِقَيْنِ وَرَبُّ الْمَغْرِبَيْنِ ۝١٧
Rabbul mashriqayni wa Rabbul maghribayni
📖 Ni Yorùbá
Oluwa ibuyo oorun mejeeji ati ibuwo oorun mejeeji

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 15-19 — Surah Ar-Rahman

15وَخَلَقَ الْجَانَّ مِن مَّارِجٍ مِّن نَّارٍ
O si seda alujannu lati ara ahon ina ti ko ni eefin
16فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
17رَبُّ الْمَشْرِقَيْنِ وَرَبُّ الْمَغْرِبَيْنِ
Oluwa ibuyo oorun mejeeji ati ibuwo oorun mejeeji
18فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
19مَرَجَ الْبَحْرَيْنِ يَلْتَقِيَانِ
(Allahu) mu odo meji (odo oniyo ati odo aladun) san pade ara won
Ar-RahmanAtokọ Kurani
78Ẹsẹ
MedinanRevelation
17Ẹsẹ

Itumọ — Ar-Rahman 17

Surah Ar-Rahman Ẹsẹ 17 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Oluwa ibuyo oorun mejeeji ati ibuwo oorun mejeeji

Surah Ẹsẹ 17/78 — Surah Ar-Rahman الرحمن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Ar-Rahman Gbọ, Surah Ar-Rahman Itumọ, Surah Ar-Rahman mp3, Surah Ar-Rahman pdf. Ẹsẹ 15–19. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers