Al-An'am · 31/165
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-An'am
قَدْ خَسِرَ الَّذِينَ كَذَّبُوا بِلِقَاءِ اللَّهِ ۖ حَتَّىٰ إِذَا جَاءَتْهُمُ السَّاعَةُ بَغْتَةً قَالُوا يَا حَسْرَتَنَا عَلَىٰ مَا فَرَّطْنَا فِيهَا وَهُمْ يَحْمِلُونَ أَوْزَارَهُمْ عَلَىٰ ظُهُورِهِمْ ۚ أَلَا سَاءَ مَا يَزِرُونَ ٣١
Transliteration
Qad khasiral lazeena kazzaboo biliqaaa`il laahi hattaaa izaa jaaa`at humus Saa`atu baghtan qaaloo yaa hasratanaa `alaa maa farratnaa feehaa wa hum yahmiloona awzaarahum `alaa zuhoorihim; alaa saaa`a ma yaziroon
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju awon t’o pe pipade Allahu (lorun) niro ti sofo debi pe nigba ti Akoko naa ba de ba won lojiji, won a wi pe: “A ka abamo lori ohun ti a fi jafira.” Won si maa ru ese won seyin won. Kiye si i, ohun ti won yoo ru lese si buru
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 29-33 — Al-An'am
29وَقَالُوا إِنْ هِيَ إِلَّا حَيَاتُنَا الدُّنْيَا وَمَا نَحْنُ بِمَبْعُوثِينَ
Won wi pe: "Ki ni (o tun je isemi orun) bi ko se isemi wa nile aye; Won ko si nii gbe wa dide (ni orun)
30وَلَوْ تَرَىٰ إِذْ وُقِفُوا عَلَىٰ رَبِّهِمْ ۚ قَالَ أَلَيْسَ هَٰذَا بِالْحَقِّ ۚ قَالُوا بَلَىٰ وَرَبِّنَا ۚ قَالَ فَذُوقُوا الْعَذَابَ بِمَا كُنتُمْ تَكْفُرُونَ
Ti o ba je pe o ri (won ni) nigba ti won ba da won duro si odo Oluwa won, O si maa so pe: “Se eyi ki i se ododo bi?” Won a si wi pe: “Rara (ododo ni), Oluwa wa.” (Allahu) so pe: “Nitori naa, e to Iya wo nitori pe e maa n sai gbagbo.”
31قَدْ خَسِرَ الَّذِينَ كَذَّبُوا بِلِقَاءِ اللَّهِ ۖ حَتَّىٰ إِذَا جَاءَتْهُمُ السَّاعَةُ بَغْتَةً قَالُوا يَا حَسْرَتَنَا عَلَىٰ مَا فَرَّطْنَا فِيهَا وَهُمْ يَحْمِلُونَ أَوْزَارَهُمْ عَلَىٰ ظُهُورِهِمْ ۚ أَلَا سَاءَ مَا يَزِرُونَ
Dajudaju awon t’o pe pipade Allahu (lorun) niro ti sofo debi pe nigba ti Akoko naa ba de ba won lojiji, won a wi pe: “A ka abamo lori ohun ti a fi jafira.” Won si maa ru ese won seyin won. Kiye si i, ohun ti won yoo ru lese si buru
32وَمَا الْحَيَاةُ الدُّنْيَا إِلَّا لَعِبٌ وَلَهْوٌ ۖ وَلَلدَّارُ الْآخِرَةُ خَيْرٌ لِّلَّذِينَ يَتَّقُونَ ۗ أَفَلَا تَعْقِلُونَ
Isemi aye ko si je kini kan bi ko se ere ati iranu. Ogba Ikeyin si loore julo fun awon t’o n beru (Allahu). Se e o se laakaye ni
33قَدْ نَعْلَمُ إِنَّهُ لَيَحْزُنُكَ الَّذِي يَقُولُونَ ۖ فَإِنَّهُمْ لَا يُكَذِّبُونَكَ وَلَٰكِنَّ الظَّالِمِينَ بِآيَاتِ اللَّهِ يَجْحَدُونَ
A kuku ti mo pe ohun ti won n wi yoo ba o ninu je. Dajudaju won ko le pe o ni opuro, sugbon awon alabosi n tako awon ayah Allahu ni
Al-An'amAtokọ Kurani
165Ẹsẹ
MeccanRevelation
31Ẹsẹ
Itumọ — Al-An'am 31
Surah Al-An'am Ẹsẹ 31 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju awon t’o pe pipade Allahu (lorun) niro ti sofo…Surah Ẹsẹ 31/165 — Al-An'am الأنعام (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-An'am Gbọ, Al-An'am Itumọ, Al-An'am mp3, Al-An'am pdf. Ẹsẹ 29–33. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








