As-Saff · 11/14
Itumọ Aṣẹ ohun — As-Saff
تُؤْمِنُونَ بِاللَّهِ وَرَسُولِهِ وَتُجَاهِدُونَ فِي سَبِيلِ اللَّهِ بِأَمْوَالِكُمْ وَأَنفُسِكُمْ ۚ ذَٰلِكُمْ خَيْرٌ لَّكُمْ إِن كُنتُمْ تَعْلَمُونَ ١١
Transliteration
Tu`minoona billaahi wa Rasoolihee wa tujaahidoona fee sabeelil laahi bi amwaalikum wa anfusikum; zaalikum khairul lakum in kuntum ta`lamoon
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
E gbagbo ninu Allahu ati Ojise Re, e jagun soju ona (esin) Allahu pelu awon dukia yin ati emi yin. Iyen loore julo fun yin ti e ba mo
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 9-13 — As-Saff
9هُوَ الَّذِي أَرْسَلَ رَسُولَهُ بِالْهُدَىٰ وَدِينِ الْحَقِّ لِيُظْهِرَهُ عَلَى الدِّينِ كُلِّهِ وَلَوْ كَرِهَ الْمُشْرِكُونَ
(Allahu) Oun ni Eni ti O fi imona ati esin ododo (’Islam) ran Ojise Re nitori ki O le fi bori esin (miiran), gbogbo re patapata, awon osebo ibaa korira re
10يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا هَلْ أَدُلُّكُمْ عَلَىٰ تِجَارَةٍ تُنجِيكُم مِّنْ عَذَابٍ أَلِيمٍ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, se ki Ng toka yin si okowo kan ti o maa gba yin la ninu iya eleta-elero
11تُؤْمِنُونَ بِاللَّهِ وَرَسُولِهِ وَتُجَاهِدُونَ فِي سَبِيلِ اللَّهِ بِأَمْوَالِكُمْ وَأَنفُسِكُمْ ۚ ذَٰلِكُمْ خَيْرٌ لَّكُمْ إِن كُنتُمْ تَعْلَمُونَ
E gbagbo ninu Allahu ati Ojise Re, e jagun soju ona (esin) Allahu pelu awon dukia yin ati emi yin. Iyen loore julo fun yin ti e ba mo
12يَغْفِرْ لَكُمْ ذُنُوبَكُمْ وَيُدْخِلْكُمْ جَنَّاتٍ تَجْرِي مِن تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ وَمَسَاكِنَ طَيِّبَةً فِي جَنَّاتِ عَدْنٍ ۚ ذَٰلِكَ الْفَوْزُ الْعَظِيمُ
(Allahu) maa fori ese yin jin yin. O si maa mu yin wo inu awon Ogba Idera, ti awon odo n san ni isale re ati awon ibugbe t’o dara ninu awon Ogba Idera gbere. Iyen ni erenje nla
13وَأُخْرَىٰ تُحِبُّونَهَا ۖ نَصْرٌ مِّنَ اللَّهِ وَفَتْحٌ قَرِيبٌ ۗ وَبَشِّرِ الْمُؤْمِنِينَ
Ati nnkan miiran ti e tun nifee si; (iyen,) aranse lati odo Allahu ati isegun t’o sunmo. Ki o si fun awon onigbagbo ododo ni iro idunnu
As-SaffAtokọ Kurani
14Ẹsẹ
MedinanRevelation
11Ẹsẹ
Itumọ — As-Saff 11
Surah As-Saff Ẹsẹ 11 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : E gbagbo ninu Allahu ati Ojise Re, e jagun soju…Surah Ẹsẹ 11/14 — As-Saff الصف (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: As-Saff Gbọ, As-Saff Itumọ, As-Saff mp3, As-Saff pdf. Ẹsẹ 9–13. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








