Al-Qalam · 49/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Qalam
لَّوْلَا أَن تَدَارَكَهُ نِعْمَةٌ مِّن رَّبِّهِ لَنُبِذَ بِالْعَرَاءِ وَهُوَ مَذْمُومٌ ٤٩
Transliteration
Law laaa an tadaara kahoo ni`matum mir rabbihee lanubiza bil`araaa`i wa huwa mazmoom
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Ti ko ba je pe ike kan lati odo Oluwa re le e ba, won iba ju u sori ile gbansasa (lati inu eja) ni eni-eebu
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 47-51 — Al-Qalam
47أَمْ عِندَهُمُ الْغَيْبُ فَهُمْ يَكْتُبُونَ
Tabi lodo won ni (walaa) ikoko wa ni won ba n ko o (sita)
48فَاصْبِرْ لِحُكْمِ رَبِّكَ وَلَا تَكُن كَصَاحِبِ الْحُوتِ إِذْ نَادَىٰ وَهُوَ مَكْظُومٌ
Nitori naa, se suuru fun idajo Oluwa re. Ki iwo ma si se da bi eleja (iyen, Anabi Yunus) nigba ti o pe (Allahu) pelu ibanuje
49لَّوْلَا أَن تَدَارَكَهُ نِعْمَةٌ مِّن رَّبِّهِ لَنُبِذَ بِالْعَرَاءِ وَهُوَ مَذْمُومٌ
Ti ko ba je pe ike kan lati odo Oluwa re le e ba, won iba ju u sori ile gbansasa (lati inu eja) ni eni-eebu
50فَاجْتَبَاهُ رَبُّهُ فَجَعَلَهُ مِنَ الصَّالِحِينَ
Nitori naa, Oluwa re sa a lesa. O si se e ni ara awon eni rere
51وَإِن يَكَادُ الَّذِينَ كَفَرُوا لَيُزْلِقُونَكَ بِأَبْصَارِهِمْ لَمَّا سَمِعُوا الذِّكْرَ وَيَقُولُونَ إِنَّهُ لَمَجْنُونٌ
Awon t’o sai gbagbo fee fi oju won gbe o subu nigba ti won gbo iranti naa. Won si n wi pe: "Dajudaju were ma ni
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
49Ẹsẹ
Itumọ — Al-Qalam 49
Surah Al-Qalam Ẹsẹ 49 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ti ko ba je pe ike kan lati odo Oluwa…Surah Ẹsẹ 49/52 — Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Qalam Gbọ, Al-Qalam Itumọ, Al-Qalam mp3, Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 47–51. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








