Al-Qalam · 50/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Qalam
فَاجْتَبَاهُ رَبُّهُ فَجَعَلَهُ مِنَ الصَّالِحِينَ ۝٥٠
Fajtabaahu rabbuhoo faja`alahoo minas saaliheen
📖 Ni Yorùbá
Nitori naa, Oluwa re sa a lesa. O si se e ni ara awon eni rere
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 48-52 — Al-Qalam

48فَاصْبِرْ لِحُكْمِ رَبِّكَ وَلَا تَكُن كَصَاحِبِ الْحُوتِ إِذْ نَادَىٰ وَهُوَ مَكْظُومٌ
Nitori naa, se suuru fun idajo Oluwa re. Ki iwo ma si se da bi eleja (iyen, Anabi Yunus) nigba ti o pe (Allahu) pelu ibanuje
49لَّوْلَا أَن تَدَارَكَهُ نِعْمَةٌ مِّن رَّبِّهِ لَنُبِذَ بِالْعَرَاءِ وَهُوَ مَذْمُومٌ
Ti ko ba je pe ike kan lati odo Oluwa re le e ba, won iba ju u sori ile gbansasa (lati inu eja) ni eni-eebu
50فَاجْتَبَاهُ رَبُّهُ فَجَعَلَهُ مِنَ الصَّالِحِينَ
Nitori naa, Oluwa re sa a lesa. O si se e ni ara awon eni rere
51وَإِن يَكَادُ الَّذِينَ كَفَرُوا لَيُزْلِقُونَكَ بِأَبْصَارِهِمْ لَمَّا سَمِعُوا الذِّكْرَ وَيَقُولُونَ إِنَّهُ لَمَجْنُونٌ
Awon t’o sai gbagbo fee fi oju won gbe o subu nigba ti won gbo iranti naa. Won si n wi pe: "Dajudaju were ma ni
52وَمَا هُوَ إِلَّا ذِكْرٌ لِّلْعَالَمِينَ
Ki si ni al-Ƙur’an bi ko se iranti fun gbogbo eda
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
50Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 50

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 50 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Nitori naa, Oluwa re sa a lesa. O si se…

Surah Ẹsẹ 50/52 — Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Qalam Gbọ, Al-Qalam Itumọ, Al-Qalam mp3, Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 48–52. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers